Anthonia Adenike Adeniji
Anthonia Adenike Adeniji (tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 1971) jẹ́ ọ̀mọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ igbákejì ọ̀jọ̀gbọ́n[1] nínú ìmò dídarí ọkọ òwò ní Yunifásítì Covenant, Ìpínlẹ̀ Ogun, Nàìjíríà.
Anthonia Adenike Adeniji | |
---|---|
Born | 25 Oṣù Kẹ̀sán 1971 Ota, Ogun, Nàìjíríà |
Institutions | Yunifásítì ti Covenant |
Alma mater | Olabisi Onabanjo University (B.Sc.) Obafemi Awolowo University (M.B.A.) Covenant University (Ph.D.) |
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Adeniji ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1971, ní Ìlú Ota, ti ìpínlẹ̀ Ogun State. Ó parí ẹ̀kọ́ B.Sc. rẹ̀ nínú ìmọ̀ ìdarí ọkọ òwò ní ọdún 1995 ní Yunifásítì Olabisi Onabanjo. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Post Graduate Diploma in Financial Management (PGDFM) ní ọdún 1997 ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ níbè ló tún ti gba àmì-ẹ̀yẹ M.B.A. ní ọdún 2000 kí ó tó gba àmì-ẹ̀yẹ P.H.D. ní Yunifásitì Covenant ní ọdún 2011.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dr. Anthonia Adenike Adeniji". Covenant University. Archived from the original on 24 November 2020. Retrieved 29 May 2020.