Anthony Afọlábí Adegbola
ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ sáyẹ́nsí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Anthony Afọlábí Adegbola (ọjọ́ìbí 24 February 1929) jẹ Òjògbón ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí sáyẹnsì Ẹranko atí Ààrẹ ilé ẹ̀kọ́ gígá tí Nàìjíríà tèlé.[1] Ní odún 1993, ọ jẹ Alàkóso tí Nigerian Academy of Science láti rọ́pò Òjògbón Akpanoluo Ikpong Ikpong Ette.[2]
Anthony Afolabi Adegbola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kejì 1929 Owerri, Ìpínlẹ̀ Imo |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Àwọn ìtọkásí
àtúnṣe- ↑ "LASPOTECH signs deed of gift to IDRDG". Daily Independent. Archived from the original on July 7, 2015. Retrieved June 9, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Members of Council". Nigerian Academy of Science (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on July 7, 2015. Retrieved June 7, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |