Ántígúà
Ántígúà (pípè /ænˈtiːɡwə/ an-TEE-gwə tabi, labele, an-TEE-gə) je erekusu kan ni West Indies, larin awon Erekusu Leeward ni agbegbe Karibeani, ohun ni erekusu gbangba orile Ántígúà àti Bàrbúdà. Antigua tumosi "atijo" ni ede Spani o si je sisoloruko latowo Christopher Columbus fun aworan kan ni Seville Cathedral, eyun Santa Maria de la Antigua—Maria Mimo ara Atijo. O tun je mimo bi Wadadli, lati inu ede awon awon Amerindia ibe tele, o si tumo si "ti wa". Iyipo erekusu na je 87 km (54 mi) be sini aala re je 281 km2 (108 sq mi). Olugbe ibe je 69,000 ni Osu Keje 2006.[1] Ohun ni o tobijulo larin awon Erekusu Leeward, ati eyi to dagbasoke julo to si ni asiki julo nitori idara ise isabewosi, ifowopamo offshore, iwofa tete lori internet ati iwofa eko to ni ile eko iwosan meji.
Native name: Wadadli | |
---|---|
Map of Antigua | |
Jẹ́ọ́gráfì | |
Ibùdó | Caribbean Sea |
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn | 17°5′N 61°48′W / 17.083°N 61.800°WCoordinates: 17°5′N 61°48′W / 17.083°N 61.800°W |
Àgbájọ erékùṣù | Leeward Islands |
Ààlà | 281 km2 (108.5 sq mi) |
Etíodò | 87 km (54.1 mi) |
Ibí tógajùlọ | 402 m (1,319 ft) |
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ | Mount Obama |
Orílẹ̀-èdè | |
Antigua and Barbuda | |
Ìlú tótóbijùlọ | St. John's (pop. 31,000) |
Demographics | |
Ìkún | 85,632 (as of July 2009 est.) |
Ìsúnmọ́ra ìkún | 245.55 /km2 (635.97 /sq mi) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 91% Black or Mulatto, 4.4% Other Mixed Race, 1.7% White, 2.9% Other |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Nation by Nation population estimate". Archived from the original on 2008-06-29. Retrieved 2010-08-23.