Antje Traue (Jẹ́mánì: [ˈantjə ˈtʁaʊə]; tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kínní ọdún 1981) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Jámánì. Ó ṣeré nínú fíìmù Gẹ̀ẹ́sì fún ìgbà àkọ́kọ́ nígbà tí ó ṣeré nínú Pandorum.[1] Ó di gbajúgbajà káàkiri àgbáyé nígbà tí ó ṣeré nínú gẹ́gẹ́ bi Faora nínú fíìmù Man of Steel (2013) àti The Flash (2023),[2][3] àti gẹ́gẹ́ bi Agnes Nielsen nínú eré Netflix kan tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Dark.

Antje Traue
Traue ní ayẹyẹ 67th Berlin International Film Festival ní ọdún 2017
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kínní 1981 (1981-01-18) (ọmọ ọdún 43)
Mittweida, East Germany
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1997–present
Websiteantjetraue.com

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Biography". Spielkind Talent Agency. Archived from the original on 31 May 2018. Retrieved 3 April 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Sneider, Jeff (27 April 2013). "Antje Traue cast as female villain in Superman". Variety. Retrieved 3 June 2013. 
  3. Strazza, Cecilia (22 March 2018). "The 10 best moments of the DC universe: No 4: The Battle of Smallville". Cinefilos (in Èdè Ítálì). Retrieved 28 March 2018. Antje Traue was outstanding in the role of Faora in Man of Steel, and the battle between her and Superman in the streets of Smallville is among the best scenes of the movie.