Antoine de Saint-Exupery Museum
Antoine de Saint Exupéry Museum jẹ́ musíọ́mù air mail kan tí ó wà ní Tarfaya, orílẹ̀ èdè Morocco.[1] Wọ́n da kalẹ̀ ní ọdún 2004, wọ́n sì da kalẹ̀ láti ṣayẹyẹ ìgbé ayé Antoine de Saint-Exupéry (1900–1944), ẹni tí ó gbé ní ilé tí musíọ́mù náà wà fún ọdún méjì, láti ọdún 1927 sí 1929, ibẹ̀ sì ló ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé rẹ̀.[2][3][4]
Antoine de Saint Exupéry Museum | |
---|---|
Antoine de Saint Exupéry Museum | |
Building | |
Location | Tarfaya, Morocco |
Coordinates | 27°56′38″N 12°55′29″W / 27.9439°N 12.9248°WCoordinates: 27°56′38″N 12°55′29″W / 27.9439°N 12.9248°W |
Ní ọdún 1927, wọ́n yan Saint-Exupéry gẹ́gẹ́ bi olóyè agbègbè Tarfaya tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀rí sí Cape Juby. Wọ́n sí musíọ́mù náà ní ọdún 2004 láti ṣayẹyẹ ìgbé ayé Anthonie àti láti sọ ìtàn ilé isé ọ̀furufú Aéropostale àti ipa rẹ̀ láti Toulouse sí Saint-Louis, Senegal. Musíọ́mù jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lopọ̀ àlejò sí ìlú náà ma ń wá.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Where 'The Little Prince' was Born". National Geographic. Archived from the original on 2013-01-23. Retrieved 2023-05-10.
- ↑ "Maroc: à Tarfaya, un musée est consacré à 'St-Ex l'écrivain' et son Petit Prince" (in fr). LExpress.fr. 2013-05-22. http://www.lexpress.fr/actualites/1/culture/maroc-a-tarfaya-un-musee-est-consacre-a-st-ex-l-ecrivain-et-son-petit-prince_1250753.html.
- ↑ Planet, Lonely. "Musée Saint-Exupéry in Tarfaya, Morocco" (in en). Lonely Planet. https://www.lonelyplanet.com/morocco/tarfaya/attractions/musee-saint-exupery/a/poi-sig/1144254/1299643.
- ↑ Limited, Alamy. "Musée de Antoine Saint Exupery, Tarfaya, Laayoune Sakia El Hamra Region, Soutwestern Marokko Stockfoto, Bild: 135368249 - Alamy". Alamy (in Èdè Jámánì). Retrieved 2017-09-06.
- ↑ Darija, Parler (2014-11-02). "Antoine de Saint Exupéry - Son lien fort avec le Maroc". lepetitjournal.com. Retrieved 2018-03-04.