Antoinette Pienaar
Antoinette Pienaar (bíi ni ọdún 1961) jẹ́ olórin, akọ̀wé àti òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.
Antoinette Pienaar | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Antoinette Pienaar 1961 Carnarvon, Northern Cape, Republic of South Africa |
Iṣẹ́ | Actress, author and singer. |
Ìgbà iṣẹ́ | 1986–present |
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Stellenbosch níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò díráma.[1] Ó gbajúmọ̀ fún ìtàn ìgbésí ayé àwọn èèyàn akíkanjú ni orílẹ̀ adúláwò tí ó má ń sọ.[2] Ó jẹ́ ọmọ iṣẹ́ fún Joannes Willemse láti ọdún 2001.[3] Láti ọdún 2003 ni òhun àti Johannes Willemse tí má ṣe atọkun ètò Amore Bekkers lórí rádíiò (Radio Sonder Grense)[4][5][6][7]. Ní ọdún 2001, ó kó àrùn cerebral malaria lẹ́yìn ìgbà tí ó lọ sí orílẹ̀ èdè Mali.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Documentary Website" Archived 20 October 2010 at the Wayback Machine.
- ↑ "Random House Publishers – Profile of Pienaar" Archived 3 March 2016 at the Wayback Machine.
- ↑ "Discover the Karoo's Herbal Wonders with Antoinette Pienaar's Website, Kruie Kraai Koning". Umuzi @ Sunday Times Books LIVE. Archived from the original on 4 September 2017. Retrieved 8 January 2018.
- ↑ "DeKAT Magazine – Special Interview with Pienaar (Pg.104–109)". Dekat.co.za. Archived from the original on 25 December 2010. Retrieved 26 November 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "DeKat Article". DeKat Article. Archived from the original on 25 December 2010. Retrieved 26 November 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Umuzi Books – Pienaar". Umuzi.book.co.za. 17 October 2008. Archived from the original on 9 March 2009. Retrieved 26 November 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Film". Healing Power of Nature. 4 May 2008. Archived from the original on 20 October 2010. Retrieved 26 November 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)