Antonio Gramsci (Àdàkọ:IPA-it) (January 22, 1891 – April 27, 1937) je was an amoye ara Itali, olukowe, oloselu ati oniro oloselu. O je ikan ninu awon oludasile ati olori Egbe Komunisti ile Itali ,o je jiju si ogba ewa latowo ijoba Fasisti Benito Mussolini. Awon iwe kiko re da le lori ituyewo asa ati isolori oloselu. O se pataki gege bi aronu ogidi ninu asa Marksisti. O gbajumo fun ajotunmo hegemoni asa gege bi ona ti orileijoba ninu awujo kapitalisti, be na sini won gba bi akopa koko ninu imoye.

Antonio Gramsci
Antonio Gramsci
OrúkọAntonio Gramsci
Ìbí(1891-01-22)Oṣù Kínní 22, 1891
Ales, Sardinia
AláìsíApril 27, 1937(1937-04-27) (ọmọ ọdún 46)
Rome, Italy
Ìgbà20th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Marxism
Ìjẹlógún ganganPolitics, Ideology, Culture
Àròwá pàtàkìHegemony, Organic Intellectual, War of Position