Gúúsù Sudan

(Àtúnjúwe láti Apágúúsù Sudan)

Gúúsù Sudan, lonibise bi Orileominira ile Gúúsù Sudan,[4] je orile-ede tileyika kan ni Ilaorun Afrika. Juba ni oluilu re. O ni bode mo Ethiopia ni ilaorun; Kenya, Uganda, ati Orileominira Oseluarailu ile Kongo ni guusu; Orileominira Aringbongan Afrika ni iwoorun; ati Sudan ni ariwa.

Republic of South Sudan

Emblem ilẹ̀ Gúúsù Sudan
Emblem
Motto: "Justice, Liberty, Prosperity"
Orin ìyìn: "South Sudan Oyee!"
Location of Gúúsù Sudan
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Juba
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish
Lílò regional languagesJuba Arabic is lingua franca around Juba. Dinka 2–3 million; other major languages are Nuer, Zande, Bari, Shilluk
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
Dinka, Nuer, Bari, Lotuko, Kuku, Zande, Mundari, Kakwa, Pojulu, Shilluk, Moru, Acholi, Madi, Lulubo, Lokoya, Toposa, Lango, Didinga, Murle, Anuak, Makaraka, Mundu, Jur, Kaliko, and others.
Orúkọ aráàlúSouth Sudanese
ÌjọbaFederal presidential democratic republic
• President
Salva Kiir Mayardit
Riek Machar
AṣòfinLegislative Assembly
Independence 
from Sudan
January 6, 2005
• Autonomy
July 9, 2005
• Independence from Sudan
July 9, 2011
Ìtóbi
• Total
619,745 km2 (239,285 sq mi) (45th)
Alábùgbé
• Estimate
7,500,000–9,700,000 (2006, UNFPA)[1]
11,000,000–13,000,000 (Southern Sudan claim, 2009)[2]
• 2008 census
8,260,490 (disputed)[3] (94th)
OwónínáSudanese pound (SDG)
Ibi àkókòUTC+3 (East Africa Time)
Àmì tẹlifóònù249