Ẹ̀so Apùlù jẹ́ Ẹ̀so tí a lè jẹ, tí á má ri látàra igi apùlù (Malus spp., pẹ̀lú àwọn tí ó nítorí igi àpùlù ṣùgbọ́n a mọ̀ rẹ̀ sí Malus domestica). Apùlù je ẹ̀so tí a lè gbin igi rẹ ní gbogbo agbègbè ayé.