Àrò jẹ́ ohun tí a má ń ló lati fi dáná oúnjẹ jíjẹ. Tí a bá fé kọ́ arò, a má ń ló igi gbígbẹ, òkúta, èyí tí a má tó pọ̀ tí a ó sì dáná sí. Ohun tí a má ń fi àrò ṣe ní ìdáná. Àwọn kan a má kọ́ ilé fún àrò, àwọn kan á sì má lo gbangba ìta ile wọn láti fi ṣe àrò ìdáná. Ìkòkò ní a má ń gbé sí orí àrò.[1] [2]

Arò

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Kitchen definition and meaning". Collins English Dictionary. 2018-03-12. Retrieved 2022-05-21. 
  2. "stove". meaning in the Cambridge English Dictionary. 2022-05-18. Retrieved 2022-05-21.