Ara sísan àsanjù
Àdàkọ:Infobox medical condition (new)
Ara sísan àsanjù ni a lè pè ní àìsàn kan tí àpọ̀jù ọ̀rá ara ènìyàn tí ó ṣe é wò pẹ̀lú oògùn yálà ti ìbílẹ̀ ni tàbí ti eléèbó.[1][2][3] tí ó lè mú ìpalára bá ìlera ẹni tí ó bá sanra náà. A lè sọ wípé ẹnìkan sanra àsanjù nígbà tí ara onítọ̀hún bá ti tóbi ju bí ó tiyẹ lọ, tí gíga tàbí kúkúrú rẹ̀ náà kò bá ti bá ojúmu.[4]Sísanra àsanjù ni ó ma ń mú aléébù bá ọ̀pọ̀ àwọn tí wọ́n bá sanra àsanjù bẹ̀rẹ̀ láti ibi ìrísí wọn bákan náà ni wọ́n ma ń sábà ní àwọn àìlera kọ̀ọ̀kan bíi àìsàn inú iṣan, ìtọ̀ ṣúgà onígun méjì,àìsàn jẹjẹrẹ àìkíílèsùn dára dára àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [5][6][7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Obesity and Cardiovascular Disease: A Scientific Statement From the American Heart Association". Circulation 143 (21): e984–e1010. May 2021. doi:10.1161/CIR.0000000000000973. PMC 8493650. PMID 33882682. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=8493650.
- ↑ CDC (21 March 2022). "Causes and Consequences of Childhood Obesity". Centers for Disease Control and Prevention (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 18 August 2022.
- ↑ "Policy Finder". American Medical Association (AMA). Retrieved 18 August 2022.
- ↑ "Criteria and Classification of Obesity in Japan and Asia-Oceania". Nutrition and Fitness: Obesity, the Metabolic Syndrome, Cardiovascular Disease, and Cancer. World Review of Nutrition and Dietetics. 94. 2005. pp. 1–12. doi:10.1159/000088200. ISBN 978-3-8055-7944-5. PMID 16145245.
- ↑ "Obesity". Lancet 366 (9492): 1197–1209. October 2005. doi:10.1016/S0140-6736(05)67483-1. PMID 16198769.
- ↑ "Obesity - Symptoms and causes". Mayo Clinic (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 November 2021.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0