Àrá kangúdù
(Àtúnjúwe láti Arakangudu)
'Síkírù Adéṣínà tí ó lògbà láàrin ọdún 1971 sí ọjọ́ kẹjọ, oṣù Kejì Ọdún,2016), tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Àrákangúdù, jẹ́ òṣèré omo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún jẹ́ Olùdarí àti olóòtú sinimá. [1] Ó jẹ́ gbajúgbajà nípa kí kópa gégé bí Oníṣègùn, Ọlọ́ṣà tàbí ògbóǹtarìgì Aláwo nínú àwọn fíìmù tí ó ti kópa.[2]Ní ọjọ kẹjọ, oṣù Kejì Ọdún Ẹgbàá-lé-mẹ́ẹ̀dógún ni ọ ṣàìsí ní ilé rẹ ní Kaduna, apá ìha àríwá Nàìjíríà.[3][4]
Àwọn fíìmù tí ó ti kópa
àtúnṣe- Tèmi Ni, Tì ẹ Kọ́
- Ìdùnú Mi
- Ìlù Gángan
- Ògbólògbó
- Ìyà Ojú Ogun
- Èrè Àgbèrè
- Àgbẹ̀dẹ Ògún
- Àgbà Òṣùgbó
- Ajé Olókun
- Ìyá Ọkọ Bournvita
- Ìgbà Òwúrọ̀
- Ayaba Òòṣà
- Àjànà orò
- Fìjàbí
- Ojú Ọ̀daràn Ré