Aramide Sarumoh, (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹfà ọdún 1985),[1] tí a mọ̀ látàrí iṣẹ́ rẹ̀ sí Aramide, jẹ́ olórin àti óǹkọrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[2] ó fi orin rẹ̀ "Iwo Nikan" gba àmì-ẹ̀yẹ iṣẹ́ ohùn tí ó dára jù lọ níbi ayẹyẹ Headies ti ọdún 2015.[3] Aramide kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmò ìjìnlè nípa òṣèlú ní University of Jos.

Aramide
Aramide
Background information
Orúkọ àbísọAramide Sarumoh
Ọjọ́ìbí22 June 1985
Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Ibadan, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
Instruments
Years active2011-present
LabelsArry Moore
Associated acts
Websitearamidemusic.com

Ní ọdún 2019, Ilé-ẹ̀kọ́ The Recording Academy yan Aramide sí ìgbìmò ìjọba ti ilé-ẹ̀kọ́ náà tí ó wà ní ilè Washington, D.C. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Aramide celebrates birthday with colourful photos". PM News Nigeria. Retrieved 9 July 2016. 
  2. "Aramide Biography". Aramide. 
  3. "Full list of winners @ The Headies 2015". 2 January 2016. http://www.vanguardngr.com/2016/01/full-list-of-winners-the-headies-2015/. 
  4. "Aramide appointed by the The[sic Recording Academy (the Grammys) as a Board of Governor for the Washington, D.C. Chapter"]. 16 June 2019. https://www.aramidemusic.com/home/blog/aramide-appointed-by-the-the-recording-academy-the-grammys-as-a-board-of-governor-for-the-washingt.