Aranso
Aránṣọ ni ẹnikẹ́ní tí ó ti yan láti máa so aṣọ pọ̀ tàbí se àtúnṣe aṣọ tí a ti rán tẹ̀lẹ̀(bíí àpẹẹrẹ, ẹ̀wù, ṣòkòtò àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ) láti mú kí o ṣe déédé ẹni tí a dáa fún un.[1] Aránṣọ gbúdọ̀ jẹ́ ẹni tí ó ti ní ìmọ̀ tẹ́lẹ̀, yálà kí ó ti kọ́ọ ṣáájú tàbí kí ó jogún báa lọ́wọ́ ìyá tàbí bàbá rè. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ní ojú ọnà leè sé.
àtúnṣeÀwọn gbajúgbajà aránṣọ pọ̀ káàkiri gbogbo orílèèdè lára wọn ni: Yomi casuals, Lumini, Tania, Treasure stitches, Bvic stitches àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ
Àwọn ohun èlò tí a fí n bẹ̀rẹ̀ aṣọ rírán ni:
Òwú
Abẹ́rẹ́
ìwọ̀n
Efun
Áyọ́ọ́nù
sísọ́ọ́sì
Mọsíínì
Àwọn ìtọ́kasí
https://www.thesprucecrafts.com/sewing-tools-and-equipment-to-sew-4122025
- ↑ "Definition of TAILOR". Merriam-Webster. 2023-02-13. Retrieved 2023-02-14.
- ↑ Colgrove, Debbie (2007-02-01). "Build Your Own Sewing Kit With These Essential Tools". The Spruce Crafts. Retrieved 2023-02-14.