Archibald Boyce Monwabisi Mafeje (30 March 1936 – 28 March 2007), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Archie Mafeje, jẹ́ onímọ̀-ìjìnlẹ̀ àṣà nípa ẹ̀dá ènìyàn àti ajà-fún-ìmúgbòrò-àṣà ti South Africa. Gẹ́gẹ́ bí ẹni tí wọ́n bí ní Eastern Cape, ó gba oyè ẹ̀kọ́ gíga láti University of Cape Town (UCT) àti University of Cambridge. Ó di ọ̀jọ̀gbọ́n ní onírúurú yunifásítì ní Yúróòpù, Àríwá Amẹ́ríkà, àti Áfíríkà. Púpọ̀ nínú iṣé rẹ̀ ni ó lò ní ìtaSouth Africa ẹlẹ́yàmẹyà lẹ́yìn tí a dènà iṣẹ́ ìkọ́ni rẹ̀ ní UCT ní ọdún 1968.

Archie Mafẹje
Archie Mafeje
ÌbíArchibald Boyce Monwabisi Mafeje
(1936-03-30)30 Oṣù Kẹta 1936
Gubenxa, Ngcobo (Thembuland), Cape Province, Union of South Africa
Aláìsí28 March 2007(2007-03-28) (ọmọ ọdún 70)
Pretoria, Gauteng, South Africa
Ará ìlẹ̀
PápáSocial anthropology
Political Anthropology
Urban Sociology
African history
Ilé-ẹ̀kọ́University of Dar Es Salaam
Institute of Social Studies
CODESRIA
University of Namibia
American University in Cairo
Doctoral advisorAudrey Richards
Other academic advisorsMonica Wilson (MA)
Ó gbajúmọ̀ fúnMafeje Affair
Anti-apartheid movement
Decolonisation of African anthropology

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe