Ariane Astrid Atodji (tí wọ́n bí ní ọdún 1980) jẹ́ olùdarí eré, olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdèKamẹrúùnù.[1] Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ tó fi mọ́ Koundi et le Jeudi national àti La souffrance est une école de sagesse.[2]

Ariane Astrid Atodji
أريان أستريد أتودجي
Ọjọ́ìbíAriane Astrid Atodji
1980
Nguelemendouka, Cameroon
Orílẹ̀-èdèCameroon
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Yaoundé
Iṣẹ́Director, producer, screen writer, journalist, actress
Ìgbà iṣẹ́2004–present

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ariane Astrid Atodji: Director". elcinema. Retrieved 7 October 2020. 
  2. "Ariane Astrid Atodji: Director". allocine. Retrieved 7 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe