Ariela Barer tí wọ́n bí ní ọjọ́ oṣù Kẹrìnlá oṣù Kẹwàá ọdún 1998, jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tí ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Hulu tí ó jẹ́ ìpele Runaways gẹ́gẹ́ bí Gert Yorkes

Ariela Barer
Barer in 2018
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹ̀wá 1998 (1998-10-14) (ọmọ ọdún 26)
Iṣẹ́
  • Actress
  • singer
Ìgbà iṣẹ́2007–present
Àwọn olùbátanLibe Barer (sister)

Ìgbà èwe rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ Jew[1] TheirẸ̀gbọ́n rẹ̀ Libe Barer náà jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé.

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ariela bẹ̀rẹ̀.ṣíṣe ní ìgba tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́ta, amọ́ tí ó mu iṣẹ́ náà ní ọ̀kúnkúndùn ní ìgbà tí ó di ọmọ ọdún Mẹ́sàn án. Ó ti kópa nínú àwọn eré oríṣiríṣi ati awọn àwo orin onírúurú bíi The Love-Inns.[2]Ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Gert Yorkes nínú eré Runaways, tí wọ́n kọ́kọ́ gbé jáde ní Hulu.[3] Ó tún kópa bí Carmen nínú eré One Day at a Time.

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ní inú oṣù Kọkànlá ọdún 2016, Barer fi léde wípé ènìyàn oníbálòpọ̀ akọ-sákọ ni òun ní orí ìkànnì Twitter rẹ̀. [4][5] and has given their pronouns as 'they/them' on their Instagram profile, indicating they are non-binary.[6]


Àwọn àṣàyàn eré.rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Notes
2009 An American Girl: Chrissa Stands Strong Sonali Matthews Direct-to-video
Stellina Blue Kamand
2011 All Kids Count Maria
2017 A Place I'd Like To Be Short film
2018 Ladyworld Olivia

Eré.orí.ẹ̀rọ amóhù-máwòrán

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Notes
2007 Yo Gabba Gabba! Super Martian Robot Girl (voice) Recurring
2008 ER Jasmine Escalante Episode: "Life After Death"
90210 Rana Shirazi Episode: "Games People Play"
2009 Valentine Young Wendy Episode: "She's Gone"
Weeds Scout Episode: "Perro Insano"
2011 Keenan's Crush Samantha 4 episodes
2012 New Girl Young Cece 2 episodes
2013 King John Sofie Television film
2014 Modern Family Sophie Episode: "And One to Grow On"
I Didn't Do It Megan Episode: "Ball or Nothing"
Gortimer Gibbon's Life on Normal Street Esther Pendragon Episode: "Ranger and the Legend of Pendragon's Gavel"
2015 Liv and Maddie Shayna Episode: "Muffler-A-Rooney"
The Thundermans Kylie Episode: "Exit Stage Theft"
2016 K.C. Undercover Alexis McCreery Episode: "Undercover Mother"
2017 One Day at a Time Carmen 4 episodes
2017–2018 Atypical Bailey Bennett 7 episodes
2017–2019 Runaways Gertrude "Gert" Yorkes Main cast
2020 Grey's Anatomy Paula Episode: "Life on Mars?"
2021 Rebel[7]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "'One Day at a Time's Goth Carmen Is Now a Superhero on Marvel's Runaways". remezcla.com. 
  2. "The Love-Inns". Bandcamp. Retrieved July 28, 2017. 
  3. Strom, Marc (February 2, 2017). "Marvel's Runaways Finds Its Cast". Marvel.com. Archived from the original on February 3, 2017. Retrieved February 2, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Mey (December 24, 2017). "Ariela Barer is Gay: "One Day at a Time" and "Runaways" Star Comes Out on Twitter, Happy Holigays Everybody". Autostraddle. Retrieved May 8, 2018. 
  5. "Ariela Barer on Twitter". Twitter. Retrieved February 7, 2019. 
  6. https://www.instagram.com/arielabarer/?hl=en
  7. "Rebel Drama From Grey's Boss, Starring Katey Sagal, Gets Series Order at ABC". TVLine.com. Retrieved September 18, 2020. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control