Arnold Smith
(Àtúnjúwe láti Arnold)
Arnold Cantwell Smith, OC, CH (hon.) (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún odun 1915 tí ó sì kú ní ọjọ́ keje oṣù kejì ọdún 1994) jẹ́ dípúlómáàtì ará orílẹ̀-èdè Canada. Òun ni Akọ̀wé Àgbà Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè àkókò, ó sì wà nípò láti ọdún 1996 títí wọ ọdún 1975.
Arnold Cantwell Smith | |
---|---|
1st Secretary-General of the Commonwealth of Nations | |
In office 1 July 1965 – 30 June 1975 | |
Head | Elizabeth II |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Sir Shridath Ramphal |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kínní 1915 |
Aláìsí | 7 February 1994 | (ọmọ ọdún 79)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Canadian |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |