Aroko Alarinyanjiyan
Aròkọ Alárínyànjiyàn jẹ aroko ti a maa n se fami- n- fa lori lori koko oro kan; yala lati segbe leyin re tabi tako o.[1]
Bi a ba n se aroko alariyanjiyan , a ni lati maa fi si otun ki a si ma fi si osi ni ori koko oro naa nipa sise alaye anfani ati aleebu okookan nipa awon koko oro inu akori wa. Ninu aroko alariyanjiyan, a kii role apa kan da apa kan si nigba ti a ba n se alaye ninu ariyanjiyan wa., amo a o wa fidi eyi ti a ba fara mọ̀ jùlọ múlẹ nínú ìkádìí wa.
Apeere aroko alariyanjiyan
àtúnṣe*Ile-eko ijoba dara ju lle-edo aladani lo.
*Ise oluko dara ju ise Dokita lo.
*Owo yeni jomo lo.
*Omobinrin dara ju omokunrin lo.
*Ise agbe dara ju ise oluko lo.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Akomolede ati Asa lori BBC: Olùkọ́ Bolanle Adekanmi kọ́ wa nípa oríṣíi Àròkọ Yorùbá tó wà". BBC News Yorùbá. 2021-02-16. Retrieved 2024-01-27.