Aroko onisorongbesi

Aroko onisorongbesi ni aroko ti a fi n se itakuoro so laarin eniyan meji tabi juu bee lo.[1]

Abuda Aroko onisorongbesi

àtúnṣe
  • O maa n ni akopa bii ere ori itage
  • Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won
  • Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi
  • Oro erin ati awada kii gbeyin, a si gbodo ye ra fun awada ako
  • Isesi won ni a maa n fi sinu ani akanmo olofo ()

Awon itokasi

àtúnṣe
  1. "Free online secondary school & High school lesson notes, Classes, etc.". StopLearn. 2023-11-07. Retrieved 2024-01-27.