Arthur Dion Hanna
Arthur Dion "A.D." Hanna (ojoibi March 7, 1928) je oloselu ara ile awon Bahama to di Gomina Agba ile awon Bahama lati 2006 de 2010.
Arthur Dion Hanna | |
---|---|
Governor General of the Bahamas | |
In office 1 February 2006 – 14 April 2010 | |
Monarch | Elizabeth II |
Alákóso Àgbà | Perry Christie Hubert Ingraham |
Asíwájú | Paul Adderley (Acting) |
Arọ́pò | Arthur Foulkes |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kẹta 1928 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Progressive Liberal Party |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |