Ashanti sí Zulu

Àwòrán ìwé Margaret Musgrove ti ọdún 1976

Ashanti sí Zulu: Àwọn àṣà ilẹ̀ Áfíríkà jẹ́ ìwé ọdún 1976 ti àwọn ọmọ kékeré èyí tí Margaret Musgrove kọ, èyí tí Leo and Diane Dillon ṣe àwọn àpèjúwe inú rẹ̀. Ó jẹ́ ìwé àkọ́kọ́ tí Musgrove yóò gbé jáde, ṣùgbọ́n tí Dillons jẹ́ oníṣẹ́ ọnà tí ó ní irírí, tí ìwé náà sì jẹ́ kí wọ́n ó gba àmì ẹ̀yẹ eléèkejì ti Caldecott Medal èyí tí wọ́n gbà léra. [1] (Àkọ́kọ́ ni Ìdí tí Ẹ̀fọ̀n fi máa ń kùn ní etí àwọn ènìyàn (Why Mosquitoes Buzz in People's Ears): ìtàn àtẹnudẹ́nu àwọn ènìyàn ẹkùn ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Áfíríkà. [1])

Ashanti to Zulu: African Traditions
Fáìlì:CM ashanti zulu.jpg
Front cover
Olùkọ̀wéMargaret Musgrove
IllustratorLeo and Diane Dillon
Cover artistDillon
CountryUnited States
GenreChildren's picture book
PublisherDial Books
Publication date
1976
ISBNÀdàkọ:ISBNT
OCLC2726240
960
LC ClassGN645 .M87

Ìwé náà ṣe àfihàn àwọn ènìyàn ilẹ̀ Áfíríkà tí wọ́n tó mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n níye, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì ń ṣe àpèjúwe nípa àṣà àti ìṣe àwọn ènìyàn náà ní pàtó.

Àwọn ènìyàn tí wọ́n kópa nínú ìwé náà:

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 American Library Association: Caldecott Medal Winners, 1938 - Present. URL accessed 27 May 2009.
Àdàkọ:S-achÀdàkọ:S-endÀdàkọ:Caldecott MedalÀdàkọ:Child-book-stubÀdàkọ:Africa-studies-stub
Preceded by
Why Mosquitoes Buzz in People's Ears
Caldecott Medal recipient
1977
Succeeded by
Noah's Ark