Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré

(Àtúnjúwe láti Asteroid belt)

Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré jẹ́ àwo róbótó tí ó wà lára ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po, tí ó wà ní bíi àárín ìyípo Mars àti Jupiter. Àwọn àkórajọ onírúurú tí kò dúró déédé tí wọ́n ń pè ní ástẹ́rọ́ìdì tàbí àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ló gba inú rẹ̀. Wọ́n tún máa ń pe ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ní ojúlówó ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tàbí ojúlówó ìgbàjá lati jẹ́ kí ìyàtọ̀ wá láàárín rẹ̀ àti àwọn míràn tí wọ́n wà lágbo ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po bíi Awon asteroidi itosi Aye ati awon asteroidi troja.[1]

Ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì gbàùngbà (ó hàn pẹ̀lú àwọ̀ funfun) wà láàrin àwọn ìgbàyípo Mars àti Jupiter.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Matt Williams (2015-08-23). "What is the Asteroid Belt?". Universe Today. Retrieved 2016-01-30. 

[1]

  1. "Mars: An Introduction to its Interior, Surface and Atmosphere". Google Books. 1956-07-03. Retrieved 2018-05-15.