Aswan Museum jẹ́ musíọ́mù kan ní Elephantine, tí ó wà ní gúúsù ìlà oòrùn Aswan, Egypt. Cecil Mallaby Firth ní ó da kalẹ̀ ní ọdún 1912.[1] Àwọn ohun tí ó wà ní Musíọ́mù náà wá láti Nubia, tí wọ́n kó síbẹ̀ nígbà tí wọ́n ń kọ́ Aswan Dam. Ní ọdún 1990, wọ́n da ẹ̀ka kan kalẹ̀ nínú musíọ́mù náà láti ma ṣe igbá terù àwọn tí wọ́n wú ní ilẹ̀.[2]

Aswan Museum
Musíọ́mù náà ní island of Elephantine, Aswan, Egypt
Building
LocationAswan, Egypt.

Àwọn ǹkan tí ó wà nínú musíọ́mù Aswan

àtúnṣe

Musíọ́mù náà ní ère ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọba àti òtòkùlú ayé àtijó, wọ́n tún ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwòrán àti àwọn ǹkan tí wọ́n wú ní òkè Elephantine.

Ó tún ní àwọn ère tí wọ́n gbé láti ara àpáta àti òkúta, ojúbọ fún òrìṣà satet àti haqanaan ayb.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Cecil Mallaby Firth; Battiscombe George Gunn (1 June 2007). Excavations at Saqqara: Teti Pyramid Cemeteries. Martino Pub.. ISBN 978-1-57898-651-4. https://books.google.com/books?id=g_H4PAAACAAJ. 
  2. "Aswan Museums and Art Galleries: Aswan, Egypt". www.aswan.world-guides.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2013-02-15. Retrieved 2018-02-24. 
  3. "متحف أسوان : جولة في التاريخ المصري على ضفاف جزيرة الفنتين". waybakmachine. 2020-05-17. Archived from the original on 2020-06-19.