Ata Tàtàṣé (Látìnì: capsicum annuum) ni wọ́n tún ń dà pe ní sweet pepper, bell pepper, paprika tàbí ní èdè Gẹ̀ẹ́sì /ˈkæpskəm/)[1][2] Ata yí ma ń ní ẹ̀yà ewébẹ̀ tí a fi ń ṣe ohun jíjẹ, tí ó ma ń ní oríṣiríṣi àwọ̀ bí :àwọ̀ pupa, funfun, àwọ̀ ewé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ata tàtàṣé kìí sábà ta ní tirẹ̀, nítorí wípé ó ma ń dùn ní tirẹ̀ .[3] agbègbè tí ata yí ti fẹ́ràn jùlọ láti màa dàgbà aí ni ibi tí ó bá lọ́ wọ́rọ́ bí ìwòn 21 to 29 °C (70 to 84 °F).[4]

àwòrán ata tàtàṣé

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Wells, John C. (2008), Longman Pronunciation Dictionary (3rd ed.), Longman, p. 123, ISBN 9781405881180 
  2. "Capsicum annuum (bell pepper)". CABI. 28 November 2017. Retrieved 15 March 2018. 
  3. Sasvari, Joanne (2005). Paprika: A Spicy Memoir from Hungary. Toronto, ON: CanWest Books. p. 202. ISBN 9781897229057. https://books.google.com/books?id=cdfiz5IS22QC&dq. Retrieved 20 October 2016. 
  4. "Growing Peppers: The Important Facts". GardenersGardening.com. Archived from the original on 27 January 2013. Retrieved 10 January 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)