Ata ilẹ̀
Ata ilẹ̀ (Látìnì: Zingiber officinale) jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ń tinú ilẹ̀ ju tàbí jáde. Wọ́n ma ń lòó lọ́pọ̀ ìgbà fún ohun èlò ìsebẹ̀, tàbí oògùn tàbí àgbo.[1] Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí kìí tètè kú tí ó sì ma ń pẹ́ kí ó tó bàjẹ́. Ọdọdún ni ata ilẹ̀ ma ń ju lójú ibi tí wọ́n bá gbìín sí tí wọ́n sì ti kórè rẹ̀.
Ìrísí rẹ̀
àtúnṣeNígbà tí ata ilẹ̀ bá ń ju, ó ma ń ga tó ìwọ̀n Mi ta kan tí ó sì ma ń ní èwe sọ́ọ́rọ́ tí ewé náà m ń rí bí ìdá olójú méjì. Àwọn èwe rẹ̀ ma ń dì pọ̀ láti ilẹ̀ ni tí wọn yóò sì ya ẹ̀ka tí wọ́n bá dókè tán. Ẹ̀wẹ̀, awọ olómi aró yẹ́lò àti pọ́pù ni èwe rẹ̀ ma ń ní.[2]
Awọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ginger, NCCIH Herbs at a Glance". US NCCIH. 1 Sep 2016. Retrieved 2 Feb 2019.
- ↑ "Zingiber officinale Roscoe". Plant resources of South-East Asia: no.13: Spices. Leiden (Netherlands): Backhuys Publishers. 1999. pp. 238–244.