Àwọn èdè Atlántíkì-Kóngò

(Àtúnjúwe láti Atlantic-Congo languages)

Ninu iyasoto awon ede Afrika, awon ede Atlántíkì-Kóngò lopojulo ninu awon ede ibatan Niger–Kongo, pelu awon sistemu ikosoto oro-oruko to wopo ninu awon ede Niger–Kongo. O ni gbogbo awon ede Niger–Kongo ayafi Mande, Dogon, Ijoid, ati die ninu Kordofanian.

Atlántíkì-Kóngò
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
Áfríkà
Ìyàsọ́tọ̀:Niger-Kóngò
  • Atlántíkì-Kóngò
Àwọn ìpín-abẹ́:
Fali (Adamawa)
Lafofa (Kordofanian)
Talodi–Heiban (Kordofanian)
Savannas (provisional)
àmìọ̀rọ̀ Ethnologue:69-16
ISO 639-5:alv