Atsede Bayisa Tesema ni a bini ọjọ kẹrin dinlogun, óṣu April ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia to da lori ayẹyẹ sisa ere loju ọna[1][2]. Bayisa yege ninu Marathon ti Chicago, Marathon ti Boston ati Marathon ti Paris lẹẹmeji.

Atsede Baysa
Atsede (centre) leading at the 2012 Chicago Marathon
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹrin 1987 (1987-04-16) (ọmọ ọdún 37)
Dire Dawa, Ethiopia
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáWomen's Sport of athletics
Achievements and titles
Personal best(s)Marathon: 2:22:03 (2012)
Half marathon: 1:07:34 (2013)

Àṣèyọri

àtúnṣe

Atsede ṣoju fun órilẹ ede Ethiopia nibi to ti kopa ninu ere sisa IAAF agbaye ti óju ọna ni ọdun 2007[3][4]. Atsede gba ami ẹyẹ ti ọla silver ninu ere gbogbo ilẹ afirica ni ọdun 2007. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye lori ere sisa[5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. woman’s race
  2. Bayisa in marathon races
  3. IAAF
  4. Marathon
  5. IAAF Gold Label Road Race.