Attiéké
Attiéké jẹ́ ìpapánu tí a maá n ṣe látara ẹ̀gẹ́, èyí tí ó gbajúmọ̀ tó sì jẹ́ oúnjẹ àṣà orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ní ìwọ-òrùn Áfríkà.