Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): B

(Àtúnjúwe láti Atumo-Ede (English-Yoruba): B)

Atumo-Ede: (Yoruba-English): B

Oju-iwe Kiini

àtúnṣe

baboon: n; (Baboon is an animal.) ìnàkí Eranko ni ìnàkí

baby:n; (The priest prayed for all babies.) omo owóÀlùfáà gbàdúrà fún gbogbo àwon omo owó

bachelor:n; (The bachelor refuses to get married.) àpón okùnrin, Àpónkùnrin náà kọ̀ láti fè ìyàwó

back:n; (Turn its back to me.) èyìn Ko èyìn rè sí mi

back:v; (Don’t back mi) ko èyìn sí; te lé Ma ko èyìn sí mi

back: adv; (He paid the money back.) padà o san owó náà padà

backwards:adv; (They asked the Child to go backwards.) padàséyìn Wón ní kí omo náà pedàséyìn

background:n; (He gave the picture he drew a very good background.) pile Ó fún àwòran tó yà ní ìpìle tó dára.

bacon:n; (Bacon is sweet with salt.) eran èyìn elédè Eran èyin elédè dùn pèlu iyò

bacteria:n; (Bacteria causes deseases.) kokoro tàbí ògbìn kékere tí a le fi èro wò. Kòkò máa n fa àrùn

bad:adj; (The man is too bad.) burú Okùnrin náa buru jù

badge: (There is a badge on Tunde’s shirt.) Ami asafihan, ìdánimò Àmi idánimò wà lára ewù Tuned

badminton: n; (Ade likes playing badminton.) Ere ìdáraya oní-bóòlù kékere àfigi gbé Ade féràn láti maa gbá bóòlù kékeré àláfígigbá.

baggage: (Adé took care of his baggage when he wanted to travel.) Àpò erù fùn ìrìn-àjò-orisìí erù ni a kó sínú àpò náà. Adé tójú àpò erù rè dáadáa nígbà tí o fé rin ìrìn-àjò bait:n; (The bait fixed into the hook was too small for the fishes to see) ìje Ije enu ìwo náà kéré fún eja láti rí

bake: v; (He baked bread.) yan Ó yan búrédi

baker:n; (The bake baked many loaves of bread.) olùyan Olùyan náà yan òpòlopo búrédì

bakery: n; (He has a bread bakery.)

ilé isé ìyan-nnkan Ó ní ilé ise ìyanbúrèdì

balance:v; (The farmer weighug sale to balance the weigh of his cocoa bags equally.) wòn lógboogba Agbè náà fì ìwon won àwon kòkó rè loogboogba

balance:n; (They have bought a new weighinh scale.) ìwon-èro tí a fi n won nnkan Won ti rà ero ìwòn tuntun

badge:n; (He sewed the badge with his shirt.) àmi O rán ami náàmó èwu re

balcony:n; (I met him at the balcony.) òdèdè tí ó lókè ni ilé ètéèsì. Ní òdèdè tí ó wà ní òke pètésì ni mo ti bá a .

bald:adj; (The old man is bald headed.) pípárí Okùnrin agbàlagbè náà ti di apárí

bale:n; (He went to the bank with bales of money.) ìdì O kó awon ìdì owó náà lo sí ilé ìfowó pamosí

bale:v; (The waste papers are bailed) dì Won dì àwon ìwé tí kò wùlò pò

ball:n; (He knows how to play footaball.) bóòlù; ohunkóhun tí a sù róbóbó Ó mò nípa bóòlù aláfesègbá

ballet:n; (I have never taken part in ballet.) ere-orúse oníyó tí kò lórò síso Nínú N kò bá won kópa nínú eré-onise oníjó tí ko lórò síso nínú rí.

balloon:n; (The Children love to play with balloos.)apo róbà tí a fé atégùn sí Awon omodé náa féràn láti máa fí apo roba tí a fé ategun sínú rè. Sere ballpoint:n; (The ballpoint has spoilt.)

kálámù ìkòwé onírin rógódó lénu kálámù ìkòwé onírin rógódó lénu náa ti bàjé

bamboo:n; (The house was built with Bamboo). oparun Oparun ni wón fi kó ilé náa

ban:v; (We shall ban smoking in the school) fi òfin dè A ó fi òfin de sìgá mimu nílé iwé

ban: n; (There is a ban on fighting in the school.) ìfòfindè Ìfòfindè wà lórí ìjà jíjà nile ìwé

banana:n; (Banana is common in Ile-Ifè) ògèdè were Ògèdè were wópò ni Ile-Ifè

band:n; (He uses bands to tie it well.) ìde; ìso Ó fi iso/ide dì í dáadáa

bandage:n; (He used bandages to tie up his wound.) ìrèpé aso tí awon orísègun fí n di ojú ogbé máa n di ojú ogbè di egbò rè

bandage:v; (He bandaged his wound tightly.) dì-di ojú egbò O di ojú ogbé rè dan-in-dan-in

bandit:n; (The man is a complete bandit) olósà Olóbà gbáà ni okùnrin náà

bang:n; (He always shuts the door with a bang.) àriwo òjijì N se ni o máa n tilekun pèlú ariwo òjiji.

bang:v; (Please don’t bang the door when you go out) ti gbà fi pariwo òjiji Máse fi ilèkùn ijéun pariwo tó o bá jade

bangle: n; (A goldsmith manufactured this bangle).ègbà owó Alágbède to ro ègbà owó yìí

banish: v; (The king banished him) lé kírò ní ile, gbè kuro (lókàn) Oba náà lé e kuro ní ìlú O gbé ìwàkuwà oko rè kúrò lókàn rè.

bank: n; (She banished herself from her husband's mis-behaviour). (He is the manage of the bank) ilé ìfowópamósí; bèbè odò Oun ni olorí ilé ìfowopamósí náà O dúró sí bèbè odò

baptise:v; (He stood at the bank of a river.) (John the Baptist baptized Jesus Christ.) rì bo oni-sàmi sí gégé bí ùàmà kìrìsìteenì. Jòhánù onítèbomi ló se ìrìbomi fún Jésù kirisiti.

bar:n; (He was called to the bar.) irin tàbí igi gbooro; iyanrì tí n dí nu odò, ibi tí tóón tí n dúró rojó ní kootu, egbé àwon agbejórò Wón pèé sínú egbé àwon agbejó rò

bar:v; (Poverty bars the way to progress.) dénà Ìsé ló máa n dínà ìlosíwájú

barbed wire: n; (He fenced his house with barbed wire).

irin tín-ún-tún-ún-rún tí a hun lónà tí nnkan kò lè koja nínú re. O fi ìrìn tín-ún-rún tún-ún-rún tí a hun pò se gbà jí ile rè ká 

barber: n; (The man is a barber.)

onígbàjámò Onígbàjámo ni okùnrin náà 

bargain: v; (He bargained with girl over the price that he would sell it for.) dúnàá- dúrà; ná- se àdéhùn oje to fé san tabí fé rà á; sàdéhun O sàdéhùn pelu omobìnrin náà; oye tó fé ta á

bark: v; (He barked like a dog.) gbó O gbó bí ajá

barrack:n; (The government has built many barracks for our soldiers.) ibùgbé awon ológun tàbi àwon agbófuiró.Àwon ìjoba tí ko òpòlopo àwon ibùgbé fún àwon ológun wa

barrel:n; (The barrel of water is at the back of the house.) agbá Agbá omi náà léhìnkìnlé

barren: adj; (The woman was barren for three years.)yàgàn, se aláìléso Obinrin náà yagan fun odún méta

barrier: n; (There are barriers on that road.) ìdína; ìdènà Ìdínà wà ní ojú ònà yen

barrow: (He put the loads in the wheel barrow.) kèkè erù èwù omo owó; ojú orórì òkú. O kó awon erù náà sínú kèké erù barter:n; (Our forefathers used to trade by barter system.)pàsípàro; ìpààrò. Pàsípààrò ni àwon bàbá nla wa máa ni se láyé àtojo

barter:v; (He bartered his clothes for shoes.) pààrò, se pàsípààrò. Ó fi aso rè pààrò fún bàta base:n; (The base of the pit is very dark.) ìsàlé, ìpìlè, ìjokòó Ìpìle kòtò náà sókùnkùn gidi

Basis: n; (What is the basis for your opinion?) pàtó Kí ni pàtó èrò okàn re?

basket: n; (He filled the basket with fruits). apèrè àgbòn Ó fí èso kún inú apèrè náa

baskeball: n; (The child is playing basketball.) bóòlu alápèrè Omo náa n gbá bóòlu alápèrè

bat: n; (He killed two bats yesterday.) (He bough a pair of new bats) àdán, òòbè Ó pa adan méjì lánàá Pákó pèlèbe tí a fi n gbá eyin orí tábílè. Ó ra pákó pèkó pelebe tuntun méjì tí a fi n gbá eyin orí tábieì

batch: (He has completed the first batch.) owó kan, àpapò nnkan Ó ti pari òwó àkókó

bathe: (We often bathe in the river on hot days.) wè: lúwèé A máa n sábàa wè nínú odò naa nìgbà oru

bathroom: n; (The students built a bathroom in their school.) balùwè; ibi ìwe-ibì ti a n wè sí Awon akekòó náà kó balùwè ní ilé-ìwé won

battery: n; (He bought a new battery to his car.) ohun ìjà ogun, àpótí ìnúnáwa. Ó ra apótí ìmúnáwa túntun sí mótò ayókélé rè

battle: n; (They have stopped the battle). ìjà, ogun Wón ti dá ijà náà dúró

battle: v; (He battle with cancer for three years).bá jà; jagun Ó bá aisan jejere jagun fún Odún méta

be: v; (You don’t know what you will be tomorrow.) jé; dà’dì O kò mo ohun tí o le jé lóla beach: n; (I will go to the beach tomorrow.) etí òkun; èbá òkun N ó lo sí etí òkun lóla

bead: (She has bought new set of beads.) ìlèkè Ó ti ra àwon ìlèke tuntun

beak: n; (He cut away the beak of the bird.) enu eye; agógó eye Ó gé enu eye náà dànú

bear: n; (Bear is not common in Africa.) bíárì-irufé erànko nlá kan tí ó n gbé ilè ótútù. bíárì ko wópò ní Ile Adúláw’`

bear: v; (Who is bearing John?) (He bears it all) jé orúk, fara dà Ta lo n jé Jòhánù Ó fara dà a gbogbo rè

beard: n; (The man shaved his beard.)

irùngbòn  Okùnrìn náa fá irùngbòn rè 

beast: n; (The beast has devoured my goat.) eranko búburú Eranko búburú ti pa ewúré mi je

beat: v; (The teacher beat the child.) lù Olùkó lu omo náà

beautiful: adj; (The lady is beautiful) tí o rewa; tí o dara Omobìnrin náà rewà

beauty: n; (She has lost her beauty.) ewà, òsó, dídára Ó ti so ewà rè nù

beckon: v; (The beckoned to me to come.) juwó sí; se àpeere sí Wón juwó sí mi kí n wá

become: (I want to become a lawyer.)dì Mo fé di agbejórò

because: conj; (I bought the book because of the child.) nítorí; tori tí Mo ra ìwè náà nítori omo náà

bed: n; ibùsùn (We have many beds in our house.) (The machine rests on a bed of concrete.) A ní ibùsùn púpò nínú ilé wa Odò; isale Èro náà sùn lé ìsàlè kannkéré náà

bed: v; (He bedded the bricks in concrete.) so pò dáindáin; to pò rémúrémú ó to àwon bíríkì náà pò rémúrémú pèlú kannkéré

beef: n; (He bought beef for me.) eran màálù Ó ra eran màálù fún mi

beetle: (The beetle is dead.)olóbòn-ùn-bon-un Olóbon-ùn-bon-ùn náà ti kú.

before: adv; (I came before him.) saájú Mo dé saájú rè

beg: v; (He begged them.) sagbe: toro: bèbè Ó bè wón.

begin: v; (We shall begin the work tomorrow.) bèrè A ó bere isé náà ní òla

bahalf: n; (He collected the money on my behalf.) ìtìléyìn; ojú rere ìdúrónípò; nípò ó gba owo náà nípò mi

behave: v; (I want you to behave well.) hùwa, lò Mo fé kí o hùwa dáadáa

behind: prep; (He stood behind the Child.) léyin Ó dúró léyìn omo náà

belief: n; (It was my belief that she went.) ìgbàgbó Ìgbàgbó mi nip é ó lo

believe: v ; (I believe in God.) gbàgbó; ní ìdánilójú Mo gbàgbó nínú olórun.

bell: n; (He rang the bell) agogo tí a n lù Ó lú agogo náà.

bellow: v; (The man was bellowing like a cow.) ke bíì máàlu Okùnrin náà n ké b’’I màálù

bellows: n; (The goldsmith bought a new bellows.) ewìrìAlágbède náa ra ewìrì tuntun

belly: n; (He stabbed the child in the belly.) ikùn Ó gún omo náà ní obè ní ikùn.

belong: v; (These books belong to me.) se tem; jé teni Tí èmi ni àwon ìwé yìí

beloved: adj; (I want there with my beloved wife.) olùfé; àyànfé. Mo lo sí ibè pèlú olólùfé ayà mi.

belt:n; (He has lost his belt.) láwàní; òjá àmùrè; ìgbànú; ìgbàjá. Ó ti so ìgbànú rè nù belt: v; (His dress was betted at the waist.) ìgbàja, so ìgbànú. Ó fi ìgbànú so aso to wò módìí dáadáa

bench:n; (He sat on a bench.) (The attorney turned to address the bench.)ìjokòó Ó jókòó lórí ìjokòó kan Ìjókòó tàbí egbé àwon adájó ni lé ejó Adájó agbà náà yí padà láti bá ìjokòó /egbé àwon adájó náà sòrò.

bend: v; (He bent the iron.) wó; tè Ó wó irin náà

bend: n; (He cut the bend from the tree.) ibi tí o wó, ibi tí o tè O gé ibi tí ó te lára igi náà

beneath: prep; (The river is flowing beneath the Bridge.) nísàlè; lábè Oni náa n sàn lábè afárá

benefit: n; (I have not seen any benefit in my coming here.) aìfààní; èrè N ko tíì rí àìfààní kankan nínú wìwá sí ibí mí

beside: prep; (He stood beside me.) ní ègbé Ó dúró ní ègbé mi

besides: pre/adv; (Basides working as a doctor, he also writes novels.) pèlúpèlú; yàtó fún. Yàtó fún síse isé ìsègun, Ó tún máa n ko ìtàn arobo

best: adj; (This house is the best in our compound.) dara julo Ile yìí ló dára julo ni adúgbò wa

betrag: v; (The woman betrayed her husband.) sòfófó, fi han, tú asírí; Sekúpa Obìnrin náà tú asírí oko rè

better:adj; (This one is better.) sàn; sàn ju; dára ju Eyí sàn jú

between: prep; (There is a strife between them.) (He stood between us.)láàrin; lágbede méjì. Ìja wà láàrin won Ó duro lágbede méjì wa

beverage:n; (Give beverages to me.) ohun mí mu Fún mi ni ohun mímù

beware:v; (Beware of bad friends.) sóra; year; kíyèsára Sóra fún àwon oré burúkú

beyond: prep; (He stands beyond the house.) níwaju; ní ìkoja Ó dúro ní ìkojá ilé náà

beyond: (He did it beyond my expectation.) kojá: jù Ó se é ju bí mo ti se fé lo

bicycle: n; (My mother bought me a bicycle.) kèké Íyá mi ra kèké fún mi lose tó koja last week.

bible: n; (The child bought a new bible.) Bibeli –ìwe mímó onígbàgbó Omo náà ra Bíbélì tuntun

bid: v; (He bade me to come near.) (He bade us farewell.) fi àse fún; fi owó lé. So-òrò ìkeyin ó fase fún mi kí n sunmó tòsí Ó sòrò ìkeyin fún wa

bid: n; (Bids were invited for construction of a new government house.) ìfowóléWón pe àwon ènìyàn fún ìfowóle kíkó ilé ijòba tuntun náà.

big: adj; (The house very big.) tóbi Ilé náà tóbi púpò

bill: n; (It is a bill that becomes a law.) àbádòfin Àbádòfin ló máa n di ofin

bin: n; (The man bought a new dust bin.) irufé garawa tabi àpótí Okunrin naa ra garawa ìkólè tuntun kan

biography: n; (They have read the biography of that man that died yesterday.) Itan ìgbésí ayé èdá Wo ti ka ìtan ìgbésí ayé Okùnrin náà tó ku lánàá .

biology: n; (Akin is a biology teacher.) Ekó ìjìnlè lórí Ohun elemi bí irúgbìn ati eranko Olùkó ekó ìjìnlè lórí ohun elemi bí irúgbìn àti eranko ní Akin.

bird: n; (Birds builds their nest on the trees.) eye Awon eye máa n ko ité won sórí Igi.

birth: n; (Birth is a providential grace.) Ìbímo; bíbímo. Oo re-òfé olórun ni ìbímo jé

biscuit: n; (He gave me a biscuit.)

akara òyìnbó O fún mi ní akara òyìnbó je

bit: adj; (Ade gave me a bit of soup.) síún, tíún, gán-ún Ade fún mi ni obè tíún

bite: v; (He bit his finger.) bù je; gé je Ó gé ìka rè je.

bitter: adj; (It is as bitter as bitter leaf.) korò Ó korò bí ewúro.

black;adj; (The black dog is here.) dúdúAjá dúdú náà wà níbí.

black: n; (Black is his best colour.) àwo dídú Àwò dídú lo féràn jù. blackboard: n; (We have blackboards in our classroom.) pátákó ìkòwé A ní pátáko ìkòwé ní yàrá ìkàwé Wa.

blade:n; (He bought two blades yesterday.) abe; abefélé; Ó ra abefélé méjì lánàá.

blame: n; (If we don’t complete this job, you will take the blame.) Ibáwì; idálébi Tí a kò bá parí sé yìí ìwo ni yóò gba ìdálébi rè.

blame: v; (He blamed the child.) bá wí; dá lébi Ó bá omo náà wí

blanket: n; (He bought a new blanket.) aso ìbora; aso itésùn Ó ra aso ìbora tuntun

blast: n; (The blast is too much.) Iró kikan; fife èfúùfù; iró ipè. Iró kíkan kíkan náà ti n pò jù.

blast: (He didn’t allow the bomb to blast.) bú gbàmù Ko jé kí àdó olorí naa bú gbamu

blaze: n; (There was a blaze of fire at the company yesterday.) òwó iná Owó iná sé yo nílé isé náà lánàà

blaze: v; (The fire blazed out unexpectedly.) sé yo Òwó iná sé yo láìròtélè. bleach: v; (He bleached his clothes.) bo: so di funfun O bó aso re.

bleach: n; (He bought new bleach yesterday.) oògùn ibódòtí Ó ra oogùn ibódòti tuntun lanáà.

bleak: adj; (The future of a lazy man is bleak.) ti ko sí ìrètí àti dár tí kò dára; tutu; tí kò dájú

bleat: v; (He asked him to bleat like a sheep.) ké bí àgùntàn ó ní kí ó ké bí aùntan

bleat: n; (The lamb gave a faint bleat.) igbe àgùntàn Òdó àgùntàn náà kò lè ké jákè.

bleed: v; (The child is bleeding through the nose.) sèjè Èjè n jade láto inú omo náà

blend: v; (He blended the thour with milk to make it sweet.) dà pò mú dùn Ó da ìyèfun náà pò mó wàrà lati mú un dùn

blend: n; (A blend of beverages is very sweet.) adalu ohun mímu máa n dùn

bless: v; (God will bless you.) bù kún Olórun yóò bù kún fun o

blew: v; (He blew air at the hot food.) (He blew air with his mouth.) fé atégùn sí Ó fé ategun sí oúnje gbígbóná náa Ó fie mi fé atégùn

blind: adj; (The man is blind.) foju. Sòkùnkun sí Okùnrin náà fójú.

blindfold: v; (Strange love has blindfolded the man.) dí loju; bo loju sú lójú Ifé àjèjì ti bo okùnrin náà lójú

blindness: n; (Blindness is troubling him.) àìrían ìfójú n dààmú rè.

blink: v; (He blinks his eyes.) séjú Ó n se ojú rè

blister: n; (The accident has cause blister on his body.) ilérórò; oówo, wúwú. Ìjàmbá náà tí jé kí iléròró wàní are rè

block: n; (He removed the block.) ìdínà O mu ìdínà náà kúrò

block: v; (He blocked the way againt the rat.) sénà; dina Ó sénà mó eku náà

blonde: adj; (The child has blonde hair.) pupa fúéúé Omo náà ní irun pupa fúéfúé

blood: n; (The child needs blood.) èjè Omo náà nílò èjè.

bloom: n; (The tree is in bloom.) ìrúwé; irudi; títanná Ìtaná igi náà famimóira.

bloom: v; (The tree is blooming.) tanná; rudi; ruwe Igi náà rudí

blossom: n; (The trees are all in blossom.) ìtànná ewèko; ìtànna igi; òdòdó Àwon igi náa wà ni àsìko ìtànná won

blossom: v; (The tree has stated blossoming since last week.) yo ìtànná; yo yètuyètu Igi náà ti n yo ìtànná láti òse to Koje

blot: n (There is a blot on the white cloth.) àbàwón Àbàwón wà lára aso funfun náà

blot: v; (He blotted his book with pen ink.) se àbàwón sí Ó se àbàwón sí wé re pèlú aró kálámù.

blouse: n; (She bought a new blouse.) èwù awòlékè obìnrin. Ó ra èwù àwàlékè tuntun.

blow: v; (He blew whistle.) (He blew air.) fun : fé Ó fun fèrè O fé atégun

blue: adj; (The cloth is blue.) (He bought a blue cloth.) òfefè Aso náà ní àwò ofefè O ra aso aláwò òfèfé

blue; n; (Blue is very good.) àwò ojú òrun; àwò ofefè Àwò ojú òrun/ èfefè dárà

blush: v; (He blushed because of the bad incidents.) bojú jé; pón lójú O bojú jé nítorí ìsèlè náà

blush: n; (She cannot hide her blush.) ibojuje; ìlejú koko Ko le fi ibójujé re pamo

boa: n; (The hunter killed a boa.) erè; ejò nlá. Ode pa erè

boar: n; (The hunter killed a boar yesterday.) ìmàdò; elédé egàn Ode náà pa ìmàdò nlá kan lánàá.

board: v; (He boarded a bus to his house.) wo; kó símú Ó wo okò lo sí ilé rè

board: n; (He put the poster up on the board.) (The board is/are unhappy about falling sales.) pátákó Ó le àwòrán náà mo ojú pátákó lókè Ìgbìmò Inú ìgbìmò náà kò dùn bí iye ojà tí wón n ní tà tí se n wale

boast: v; (Don’t boast fabout what is not yet certain for you.) fón enu. Máse fón enu fún nnkan tí ko ti í da e lójú

boast: (His boast is too much.) Ìfónu Ifónnu rè ti p`dojù.

bob: v; (He was bobbing as if he wanted to sleep.) pààrà; rìn kiri. O n paara bí eni pe ó fe jale

bob: n; (The bob you have engaged yourself in cannot favour you.) ìpààrà: ìrìnkiri; ìrìnsótè-sódò Ipààrà tí gùnlé yìí kò lè sé o ri àn fààní.

body: n; (Esau had hair all over his body.) ara Esau ní irun ni gbogbo ara rè

boil: v; (He boiled the meats they gave him.) bò O bo eran tí won fún-un.

bold: adj; (The man is very bold.) gbóyà; gbójú-gboya Okùnrin náà gbájú-gbóyà

Oju-iwe Keji

àtúnṣe

bolt: n; (He bought three small boits.) ìdè O ra awon ìdè kékèéké méta

bómà: n; (He lead the cattle to their bana.) ògbà eran; ibùgbé eran Ó da awon màálù náà wo ibùgbé Won. bomb: n; (He killed his enemies with a bomb.)

àdó olóró Ó pa àwon òtá rè pèlú adó olóró

bomb: v; (He bombed the quarters.) fi adó dóró parun Ó fi adó olora pa agbegbe náà run

bond: n; (Both of them have entered into a bond.) idè; ìmùle; iwé adéhùn Àwon méjèèjì ti se ìmùlè láàrin ara won.

bone:n; (The femur is the longest bone in the body.) egungun Egungun itan ló gùn jù ninu gbogbo àwon ègungun ara

bonfire: n; (The bonfire covers all this compound.) àkàndá má; iná nlá tí a tan síla lákòókò àriyá Akanda me nlá náà mole yìí gbogbo agbègbe yìí

bonnet:n; (He opened the bonnet of the car.) imú okò ayókélé Ó sí imú oko ayókélé náà sílè

book: n; (He was reading his book.) ìwé Ó n ka iwé rè

boo: v; (He has booked the accommodation for us.) Sètò sílè nípa sísanwo Ó tí seto ele tí a o gbé síle

bookcase:n; (He bought a new book case.) àpótí ìkówèésí Ó ra àpóti- ìkówèésí tuntun

boot: n; (The soldiers cottected new boots) (He locked the book of the car.) bàtà; èyìn okò-ibi ìkérùsí eéyìn okò. Àwon ome ológun náa gbe bàtá tuntun Ó ti èyìn okò ayokélé náà

border: n; (The stood at the border of the town.) ìpèkun : ibodè Won duro ni ìpekun ìlú nàá.

bore: v; (The bore can bore through rock.) (I have heard all his storied before they bore me/he bores me.) lu; gbé I hunnkan yìí lè lu òkútà kojá Sú; dá lágara Mo ti gbó awon ìtan ìtan re télè wón ti sú mi

bore: n; (Don’t be such a bore;) (He has a twelve-bore shotgun) ìdámilágara Má saya adámilágara báyen Oníhò; ihò gbígbéjìn Ó ní ìbon olójú/oníhò méjìlá

born: v; (He was born last year.) bí A bí I lódún tó kojá

borne: V; (He has borne three Children.) bí Ó bí omo mela

borrow:v; (I borrowed money from him.) yá; Mo yá owo lówó rè

boss: n; (The bose was annoyed with his secretary.) ogà elèisé Ogá ibi isé náà binú sí akòwé rè

botany: v; (Our teacher is very verse in botany.) èkó ìjìnlè nípa ohun ógbìn Olukó wa ni ìrò ìhìnlè nínú èjó ìjìnlè nípa ohun ògbìn.

both: adj; (Both of them are here.) méjèèjì Àwon méjèèjì wà níbí

bother: v; (Don’t bother yourself.) yo lenu; dààmú. Má yo arà re lému

bottle: (He put water in all the empty bottles.) ìgò; sago. Ó ro omi sínu gbogbo kòròfo ìgò náà.

bottom: n; (The bottom of the bottle is dirly.) ìsàle; ìpìlè; ìdí Idí ìgò náà dòtí

bought: v; (He bought a car yesterday.) rà O ra òkò ayókélé lánàá.

boulder:n; (The boulder cannot be moved.) òkúta nláribitì Òkúta nlá ribiti náà ko se e si nídìí

bounce: n; (He allow the baby a bounce before the put her on her back.)tito sókè, fifò sókè, Ó fún omo náà laaye itosoke èèkan kí o tó gbé e pòn séyìn

bounce: v; (The baby is bouncing on his mother’s back.) to; fò sókè omo náà n to sókè eéyìn ìyàá rè

boundary: n; (He showed the boundary between the two towns.) ààlà; òpin ó fí ààlá ààrin àwon ilú mejèèjì hàn mí. bouy: n; (The bouy is no more working Well.) amí lóju omi láti tóka ewu fún oko Àmì lójú omi tí ó n’tóka bí oke se ye kó rìn ko sisé dáadáa

bow:n; (The bow is no more good.) orun Orun náà ti bàjé

bow: (The bowed down for their boss.) (The congregation bowed their heads in prayer.) teríba fún; tè bere Wó tè fún ogá won Ìjo ènìyan te orí won ba fún àdúrà.

bowl: n; (He bought a new bowl.) Opón; abó kolo Ó ra opón tuntun

box: n; (He packed his clothes in a box.) àpótí Ó pa aso rè mó sínú àpótí

boy:n; (The boy has left.) odómokùnrin Odómokùnrin náa ti lo

boycott:n; (There was a boycott of election by the political parties.) àsepatì Awon ègbé òsèlu náà se àpatì ìdìbò náà.

boyctt: v; (Don’t boycott my house.) pa ti má se pa ilé mi ti.

brace: ìdè; (The brace of my trousers cuit.) ojá ; ohun tí a fi gbá nnkan. Okùn tí mo fi mú sòkòtò mi lókè ti já.

brace: v; (He braced the door with iron rod.) dè; fi gbá ó fi irín gbá ilèkùn náà.

bracelet:n; (I bought a golden bracelet yesterday.) ègbà owó mo ra ègbà owó olómi góòlù lánàá.

bracket:n; (He puts the word in a bracket.) àmì àkámó ó fi òró náà sínú àkámó

bracket: (Make sure you put all the borrwed words in bracket.) fi sínú àmì àkámó Rí ì dajú pr o fí gbogbo awon òrò ayálò sínú àkámó brag: v; (He likes to brag.) hale, se féfé yangàn ó féràn látì maa hale

braid:v; (He likes to brag.) (The lady braids her hairs.) dì hun; omobínrin náà dì irun rè

braid:n; (She prefers braid to all other styles.) irun dídì; ìhun ó feran irin dídì ju gbogbo awon àrà yòóku li a lè firun dá

brain: n; (The Child has a sharp brain.) opolo, omo náà pè.

brake: n; (The bicycle doesn’t have good brake. Ìjámu kèké náà ko ní ìjanu tí o dára

brake: v; (The driver quickly apply brake to avoid accident.) lo ìjánu Awakò náà lo ìyánu kí ìjàmbá má bà á selè

branch: n; (He cut the branches of the tree) èka ó gé àwon èka igi náà

branch:v; (He branched to the right.) yà; peka o ya sí apá òtún .

brand:n; (The good have the same brand.) àmì tó wà lára ojà títa àmì ègan. Àwon ojà náà ní àmì kan náà

brand: (He branded his own products to differentiate them from other.) sàmì sí; sàmì ègàn sí láná; kégàn Ó sàmì sí àwon òjà re láti yà wón sótò lára àwon mìíràn

brittle:adj; (The bone is vey brittle.) rorùn láti Eegun náà ròrun láti fó

broad:adj; (The road is broad.) gbòòròònà nàá gbòòrò.

broadcast: v; (He broadcast the news on the television.) fán káàkiri, tàn káàkiri ó tan ìròyìn náà kaye lórí èro móhùn-máworan

broadcast: n; (He stood against the broadcast of the program.) ìtànkáàkìrí Ó ta ko ìràn kaakìri ètò náà

broken:adj; (He threw away the broken bottle.) fífó ó da efífó ìgò náà nù

broken:v; (The bottle has broken.) Ìgò náà ti fó bronze: (The wrist watch is made from bronge.) adàlu bàbà àti ide Àdàlù bàbà àti ide ní wón fi se aago owó náa

brooch: n; (The lady always uses broocher.) ìktí òsó tí àwon obìnrin náà máa n lo ikótí osò lati fi so èwu re lórùn nigbà gbogbo.

brood: v; b (The hen broods its eggs.) sàba; pa eyin Adìe náa pa àwon eyin rè.

brood: n; (The two chicken are of the same brood.) om eye tí ìyá won jo pa nígbà kan náà Ìgbà kàn náà ní won pa awon omo ad`ye mejéèji.

brook: n; (We bathe in a brook.) odò ìsàn kékeré A wè nínú odò ìsàn kékeré

brook: v; (He brooked the suffering.) fara dà ó farad a ìnira náà

broom: n; (He gave me a broom.) owò; ìgbálè ó fún mi ní igbálè kan

broomstick:n (Give me a broomstick from the broom.) sasawo; eyo omo owo. fún mini eyo omo owo kan nínú owò yen

brother: n; (Adé is my brother) arákùnrin Arákùnrin mí ni Adé

brow: n; (The dangling stick hit my brow.) (He stood at the brow of the hill.) iwájùn orí; sónsó orí òkè Igi tó n jì dirodiro náà gbá mi níwàju orí . Ó dúró ní sónsó orí òkè.

bruis:v; (He bruised the head of the snake) tè ré; pa lara ó te ejò náà lórí mólè

bruise: n; (The ara bruises on the body of the thief.) ogbé ìtèré, ìpalára ojú ogbé wà lára olè náà

brush: v; (He brushed the dust off is cloth.) gbònnù ó gbon ìdòtí kúrò lara aso rè.

brush: n; (He bought a new brush.) owò –owò ìgbòn-nnkan –nù ó ra owò/ ìgbon-nnkan-nù tuntun

brutal: adj; (The man is too brutal.) rorò; níkà okùnrin náà rorò

brutality: n; (He showed his brutality by stabbing the Child.) ìrorò; ìsèka ó fi ìrorò rè han nípe gígún omo náà lobe

brute: n; (My husband is a brute.) ònrorò; ika onroro ni okò mi

buck: n; (Buck goes to drink at the river in the evening.) ako àgbònrín ; obúko; Ako àgbònrin a máa nmimu ni odo ìsàn ní owó àsálé bucket: n; (He bought a new bucket.) garawa ó ra garawa tuntun

buckle: n; (The shoe has two buckles.) ìdè bàtà náà ní ide méjì

buckle:v; (He buckle his shoes.) ìdè nnkan ó de bata rè

bud: n; (He pruned the new buds from the tree.) eélù ó já àwon ìdì tuntun ara igi náà kúrò

bud; v; (The orange tree has budded.) rudí; rúwè Igí osàn náà ti rudi

budge: v; (He budged the big stone.) mi; sún ó mí òkúta nlá naa

budget: n; (The president of this counting has read the budget.) ìwé ìròyìn owó ; iwe ìròyìn ètó ìsíná. Aare orílè-ede yìí tí ka iwè ètò ìsúná owó.

buffalo :v; (Buffalo is a wicked animal.) efòn Eranko búburú ni efon

bug : n; (Bed buy is among all the bugs that bite.) kòkòro; ìda; ìdun Idún wà lára àwon kokorò kékèèke tó n jèyan.

build: v; (He built a house.) kó ilé; mo o k\ó ilé building: n; (The building are very good.) ilé ti a kó Awon ilé tí wón kó náà dára

bulge: v; (when my mother came back from the market, her bag was bulging with things.) wú sóde; wú síta. Àpò ìyá mi wu pèlu orisìí awon nnkan tó rà nìgbà tí o ti ojà dé

burglear :n; (The police men have arrested the burglars.) afólé; fótéfólé –eni tí o wole onílé láti jí erù kó

bulgle : (The hunter lost his bugle.) fère ìpè ologun ode náà so fèrè rè nù

bulk  : (He bought it in bulk.) ìwon nlanlá; tìtobi ó rà a ní nlá

bull: n; He slaughter the bull.) ako màákù ó pa ako màálù naa

bulldoze: n; (The government has bought a new bulldozer.) èro ìpalèmó. Ijoba ti ra ero ìpalemó tuntun

bullet : n; (The bullet wounded him.) ota ìbon; ahaya ota ìbon náa pá eara

bullock: n; (He slaughter a bullock.) egboro ako màálù; odá màálu ó pa egboro ato màálù kan bully: (The man is a complete bully.) aninilára; ayonilénu Ayonilénu pómbélé ni okùnrin náà

bully:v; (The teacher always bullies on his students.) ipá láyà; kígbe mó olùkó náà máa n pá àwon akékòó rè láyá.

bully goat: n’ (The man has a bully goat.) obúko tabi ako ewúre òkùnrin náa ni ako ewúré kan bump: n; (The bump is still there.) wíwú soke wiwu náà sì wa mibe

bump:v; (He bumped against chair.) ko lù ó ko lu àga

bumper: n; (He hit the bumper of the car.) ìdáàbòbò okò ó ko lu ìdáàbòbò okò ayókélé náà. bun: n; (He ate bun yesterday.) akara róbóto àláàádùn ó je àkàrà roboto aláàádun lánàná

bunch: (He bounght a bunch of plantain.) siiri; akója nnkan ó ra siiri ògèdè àgbagbà bindle: n; (The bundles of stick are plenty.) ìdì; erù. Àwon ìdì igi náà pò

bungalow: n; (He has buit a bungalow.) irúfé ilé ile kan ó ti kó irúfé ilé ilè kan

bunk: n; (They put two or three bunks on top of another to save place.) ibùsin tí se mó ògiri wón to ibùsùn meji tabi meta léra, nitorí ààyè

burial:n; (His burial will be on Tuesday.) ayeye ìsìnkú ojó ìségun ní ayeye ìsùn kú rè

burn: v; (Fires were burning all over they city.) (The house burned to the ground.) jònà; jó Iná n jò ní gbogbo ìlú naa Ile náà jóná pátápátá

burrow: n; (I saw a burrow yesterday.) ihò ehoro mo rí ihò ehoro kan lanaa

burrow: v; (The rodent burrowed its way into the sand.) gbého Eku náà gbéhò rè sínú iyanrin burst: v; (The tyre will burst if you blow it up any more.) bé; fó; tú jade Táyà náa yóò bé tí o bá tún fé e sí

burst: n; (There was a burst of laugher from the child.) ìsè òjiji Awon omo náà bu sérìn-ín lójiji

bury: v; (He was buried in his home town.) (The dog buried the bone it had found.) sin; bò mole: sìnkú. Wón sin in ìlúu rè. Ajá náà bo eegun tó rí mole

bus : n; (Shall we walk or go by bus?) oko se kí a fí ese rin ni àbí kí a wo okò ?

bush : n; (There is only one bush between my village and the town.) igbó : igbé Igbo kan soso ló wà láàrin abúlé mi ati ilú náà.

bushfool : n; (He killed one bushfool yesterday.) àparò ó pa àparò kan lánàá business: n; (My business is selling fruit.) (leave me alone mind your business.) isé; òwò; nnkan tó kan ení. Èso títà ni òwò mi Fi mí sílè, gbájú mó ohun tó kàn ọ́.

busy :v; (I am busy.) sise lówó; mo n sise lówó busy: adj; (He is a very busy man.) náà láápon okùnrin náàláápon

but : conj; (His mother won’t be here, but his father might.) sùgbón ìjá è le má wà níbí sùgbon bàbáa rè le wà níbí.

butcher: n; (His father is a butcher.) alápata Alápatà nì bàbáa rè

bulter : n; (Fry the onions in butter.) orí (àmó) Dín àlùbósà náà òrí àmo

bulter : v; (She buttered four tick slices of bread.) fí orí (amó) sí buredi ó fi orí (amo) sí awon ègé buredi kíki merín

butterfly :n; (She is like a butterfly.) labalábá ó rí bí ì labalaba

button : (He pressed the button.) ìdè ó te ìdè náà

button: v; (She hurridly button her blouse.) fi ìdè dè ó yara de ìde èwu rè

buy : v; (My father but a new cloth.) rà bàbá mí ra aso tuntun.

buzz : v; (The insects were buzzing around the room.) kùn bí olóbòn-ùn-bon-ùn. Kòkòrò náà n kùn káàkiri iyèwù

buzz : n; (The buzz of the bees is too much.) kíkùn kíkùn awon oyin náà tip ò ju

by : prep; (A house is by the river.) lébàáIlé kan wà lébàá

by :and; (He came in by the door.) nípase ó gba ojú ònà wole

brim : n; (We stood at the brim of the river.) bèbà odò A dúró ní bèbè odò naa brim : v; (His eyes were brimmed with tears.) kún fun; kún ojú rè kún fún omijé

bring : v; (He wants to go and bring the money.) mú wá ó fé lo mú owó náà wá

bring up : v; (He brought up the child.) tó ó tó omo náà dàgbà

brisk : adj; (The man is very brisk.) já fafa; yára okùnrin náà já fáfá dáadáa

brass : adj; (He bought a brass plate.) oníde ó ra abó oníde

brass: n; (The brass is very good.) ide. Ide náà dára gidigidi

brave : v; (The child is very brave.) láyà: gbójú-gbóyà; gbóyà. Omo náà gbóyà dáadáa

bread : n; (I ate bread yesterday.) àkàrà Mo je àkàrà lánàá

breadfruit: (He ate breadfruit.) N.b “gbere” (is a borrowed word, it is borrowed from breadfruit. It is short end from “gberebúùtù”

gbere; -irúfé èso igi kan ó je gbere. 

breadth: n; (He calculated the breadth of the House.) ìbú; gbígbòòrò ó won ìbú ilé náà

break: v; (He broke the stick.) fo; sé; dá ó dá opá náà

break :n; (They have gone on long break.) ìsimi; dídá Wón ti lo nínú olójó gbooro.

breakfast : n; (I have eaten my breakfast.) oúnje òwúrò mo ti je oúnjè òwúrò

breast: n; (Covered her breat with cloth.) oyàn; omu. ó fi aso bo ọyàn rẹ.

breastfeed: v; (She breastfeeds her baby everyday.) fún omo lóyàn ó máa n fún omo re lóyàn lójoojúmò

breath: n; (Breath is very important for all living things.) èémí Èémí se pàtàkí fun gbogbo ohun To bá n mí

breathe : (He breathed out.) mí ó mí jade

breed: v; (I breed goats.) se ìtójú; bí; lóyún tó; sìn mo n se ìtoju/sìn ewúré

breed: n; (I like this breed of goats.) irufé ohun òsùn; eyà ohun òsìn mo feran eya ewúré yìí

breeder:n; (My father is a breeder of goats.) olùtójú; olùsìn olutójú ewure ni bàbà mi

breeze: n; (The breeze is very cool.) atégun tó n fé yéè Atégun náà tutu dáadáa

brew: v; (He brews all sorts of drinks.) pon otí ó máa n pon orisìírisìí otí mímu.

brewry: n; (He sets up a brewry.) ilé ìpon otí ó da ilé ìpon otí sílè

bribe: v; (He bribed his boss.) fún ní rìbá tabi àbètélè o fún ogá rè ní àbètélè

bribe: n; (He took bribe from the man.) àbètélè; owó èyìn; rìbá ó gba àbètéle lówó okùnrin náà

brick: n; (He used many bricks to build the house.) amò tí a gé tí a n fi kólé ó fi òpòlopo amò tí a gé kó ilé náà

bridal: adj; (The bridal party is very interesting.) tí ó je mo ti ìyàwó Àsè igbeyìwó náà dùn

bridegroom: n; (The bridegroom has arrived.) oko ìyàwó, oko ìyàwó ti dé

bride: n; (The bride has come.) ìyàwó asesegbé Ìyàwó àsèsègbé náà ti de

bridemaid: n; (The girl is a bridemaid.) egbé ìyàwó; omoìyàwó ní omobìnrin náà

bridge : n; (The built a bruge over the river.) afárá wón mo afárá sórí odò náà. bridge: (He bridged the river.) safárá sí; ó safárá sí orí odò náà

bridle:n; (The bridle of the horse is cut.) ìyánu; ìjánu esin náà ti já

brief: adj; (I want you to be very brief.) sékí; kíún; sókí Sékí ní mo fè kì o sòrò

briefcase:n; (He bought a new briefcase.) ohun èlò ìkérùsí ó rí ohun èlò ìkèrùsí tuntun

briefy: adv; (The man told us what happerened to him briefly.) láìfa òrò gùn ; ní kúkúrú okùnrin náà so ohun tó sele sí i fún wa ní kúkúrú

brigade:n; (All the membery of brigade were there.) egbé omo-ogun elésin tàbí elésè Gbogbo awon omo ogun egbe elésìn ló wà níbè

bright: adj; (The sun is very bright.) (The Child is very bright.) tí ó tan imólè, tí ó mole, tí o dán, oòrùn náà mole dáadáa. Tí ó gbón; tí ó ní làá làáyè. Omo náà nì làákàyè dáadáa

brilliant: adj; (The child is very brillant.) lóye; dídán omo náà ní òye dáadáa