Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): B

ATÚMỌ̀-ÈDÈ (YORÙBÁ-ENGLISH):B

1. box (n); Àpótí: I kept my dresses inside Sade’s box. (Mo kó aṣọ sínú àpótí sadé).

2. bov (v); Ẹ̀sẹ́: Olu boxed me in the nose. (Olú kàn mí ní ẹ̀sẹ́ ni imú).

3. boy (n); Ọmọkùnrin: Àdùkẹ́’s mummy gave birth to a baby boy. (Ìyá Àdùkẹ́ bí ọmọ ọkùnrin).

4. boycott (v): Já. We Boycott the load because it was too expensive. (A já ẹrù náà sílẹ̀, nítórí pé ó ti wọ́n jù).

5. boycott (n); pa tì: You Boycott me as of no account. (Àpatì ló pa mí tì).

6. bracelet (n); Ẹ̀gbà omì ọmọ́: Bracelet is in her hand. (Ẹ̀gbà omì ọwọ́ wà ní ọwọ́ rẹ̀).

7. braces (verb); dè: He brace up the trouser. (Ó de sòkòtò náà sókè).

8. bracket (noun); àmì: He gave me a signal. (Ó fàmì hàn mí).

9. brag (verb); halẹ̀: He made empty brag to me. (Ó hàlẹ̀ mọ́ mi).

10. braid (verb); dì: She braid her hair in wisps unth black thread. (Títí di irun orí rẹ̀ ní òwú dúdú).

11. braid (noun); irún dídì. She wears her hair in braids. (Irun orí rẹ̀ wà ní dídì).

12. brain (noun); Ọpọlọ: He fell and dashed his brain out on the rocks. (Ó subú, ó fi ọpọlọ gbá òkúta).

13. brake (nonu); Ìjánu kẹ̀kẹ́: The brake of the bicycle is not good. (Ìjánu kẹ̀kẹ́ náà kò dára).

14. branch (noun); ẹ̀ka igi: He dimbed up the tree and hid among the branch. (Ó gun igi, ó sa pamọ́ si ara ẹ̀ka igi).

15. branch (verb): pèka: The bank has branches in all posts of the Country. (Ìle ìfowópamọ́ náà pẹ̀ka kaàkiri orílẹ̀ èdè yìí.

16. brass (noun); idẹ: Brass con not made oduduwa’s axe. (Idẹ̀ kò se é nọ àáké òdùduwà).

17. brave (adjective); gbóyà: It was brave of him to enter the buring building. (O gbóyà lati wo inú ilé tí ó ń jó).

18. bread (noun) Àkàrà: He eats bread. (Ọmọ náà fẹ àkàrà).

19. break (verb); fọ́: He break my bread with a cudget. (Ó fọ́ mi ní kùmọ̀ lórí).

20. break fast (nonu); ónújẹ àárọ̀: I am eating my breakfast. (Mò ń jẹ óńjẹ àárọ̀ mi).

21. Breast (nonu); ọmí: The new baby is suckling her mother’s breast. (Ọmọ titun náà ńmu omí ìyá rẹ̀).

22. breath (noun); èémí: The breath of the boy is not okay. (Èémí ọmọ náà kò dára).

23. breathe (verb) mí: He breathe loudly. (Ó ń mú sókè).

24. breed (verb); se ìtọ́jú: The Doctor breed up the patient. (Dókítà se ìtójú aláìsàn).

25. breeze (noun); Atẹ́gùn: The breeze carried the money away. (Atẹ́gùn gbé owó náà lọ).

26. brew (verb); pọn ọtí: Bọlá brewed alcoholicdrink. (Bọ́lá pọn ọtí ògógóró).

27. briber (noun) Àbẹ̀tẹ́lẹ̀: Bribery is prohibited. (Àbètẹ́lẹ̀ kò dára).

28. Bribe (verb); bẹ àbẹ̀tẹ́lẹ̀: The child was bribed to take the nasty medicine. (Ọmọ náà bẹ àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ki o to gba òògùn rẹ̀).

29. brick (noun): amọ̀: A house made of red brick. (Ilé náà jẹ́ alámọ̀ pupa.

30. Bride (noun) Ìyàwó: Bride will bear a children and then as a make weight produce the teath. (Ìyàwó á bí mẹ́sàn-án, á fi ọ̀kan se ẹ̀nì).

31. Bridegroom (noun); Ọkọ ìyàwó: Ilè bridegrrom has come. (Ọkọ ìyàwó ti wọlé dé).

32. bridge (noun); Afárá: The bridge has collapsed. (Afárá náà ti yẹ̀

33. bridge (verb); safárá sí He formed a bridge on the water. (Ó safárá si ojú omi

34. bridle (noun); Ìjánu: The bridle of the car is not good. (Ìjánu ọkọ̀ náà kò dára).

35. brigade (noun); Ẹgbẹ́ ọmọ ogun: The brigade donated a large of money. (Ẹgbẹ́ ọmọ ogun ni o da owo ju(.

36. bright (adjective); tan ìmọ́lẹ̀: Sunshine is bright. (Òòrùn náà tan ìmọ́lẹ̀).

37. brilliant (adjective); Títànsàn: He is a brilliant boy. (Ìrawọ̀ ọmọ náà tàn sàn).

38. brim (noun); bèbè odò: I saw the child at a brim side. (bèbè odò ni a ti rí ọmọ náà).

39. bring (verb); mú wá: Ile soldiers came back bringing ‘ten’ prisoners. (Jagunjagun náà mú wá àwọn ẹlẹ́wọ̀n mẹ́wàá).

40. brittle (adjective); rerun wómú: Ade’s car had an accident and brittle. (Ọkọ̀ Adé forí sogi ó rún wómú wómú).

41. broad (adjective); gbòrò: The road is extensive. (Ojú ọ̀nà náà gbòrò).

42. broadcast (adjective); fún káàkiri: The British broadcasting corporation. (Ile ìgbìmọ̀ fún káàkiri ti alámọ̀ funfun).

43. broken (adjective); fífọ́: Olu has broken all the plates. (Olú ti sọ gbogbo àwo di fífọ́).

44. bronze (noun): àdàlù bàbà: A bronze statue is in our house. (Àdàlù bàbà wà ní ilé wa).

45. brooch (noun): ohun ọ̀ṣọ́: Sọlá put brooch in her dress. (Sọlá fi ohun ọ̀sọ́ si ara asọ rẹ̀).

46. brood (verb); Sàba lórí: The hen brood on her eggs. (Adìyẹ náà sàba lórí ẹyin rẹ̀).

47. broom (noun); ìgbálẹ̀: Sọlá bought a broom. (Sọlá ra ìgbálẹ̀).

48. brother (noun); arákùnrin: My man has come. (Arákùnrin mi ti dé).

49. brought mu; Ade brought his dog. (Adé mú ajá rẹ wá).

50. brow (noun), iwájú: He is in brow of me. (Ó wà níwájú mí).

51. bruise (noun); Ọgbẹ́: The child inflicted a bruise. (Ọmọ́ náà gba ọgbẹ́).

52. bruise (verb); ha: This stick bruised my skin. (Igi yìí ha mi lára).

53. brute (verb); fí ọwọ́ gbọ̀n: (He brush the letter out of my hand. (Ó fi ọwọ́ gbọn lẹ́tà dànù ní ọwọ́ mi).

54. brute (noun): Òmùgọ̀: He is brute. (Ọmọ yìí ya òmùgọ̀).

55. bubble (noun); ìtànjẹ: He speaks a very bubble ides. (Ó sọ àbá ìtànjẹ).

56. bubble (verb) rú sókè: The water bubbed up through the sand. (Omi náà rú sókè mọ́ ìyẹ̀pẹ̀).

57. buck (noun); akọ àgbọ̀nrín: The buck has eaten the okro in the faim. (Akọ àgbọ̀nrín náà ti jẹ ilá tán ni oko.

58. bucket (noun) garawa: The rain is falling inside the bucket. (Òjò ń rò sínú garawa).

59. bud (noun); ehu ohun ọ̀gbìn: The trees are in bud. (Àwọn igi náà wà ní ehu ohun ọ̀gbìn).

60. bud (verb); hù: The maize bud out. (Àgbàdo náà hù jáde).

61. budge (verb); míra: I can’t budge it. (Mi ò lè mira kúrò).

62. budget (noun); ìwé ìròhìn owó: A budget was made by Government. (Oríṣìí ìwé ìròhùn owó ìlú ni gómìnà kà).

63. buffalo (noun); ẹfọn: The buffalo are too many in India. (Ẹranko ẹ̀fọ̀n tí pọ̀jù ni ìlẹ́ Indíà).

64. bug (noun); ìda: bugs are in his cloth. (ìda wà nínú asọ rẹ̀).

65. bugle (noun) ìfẹ́: He bugle to me. (Ó fife pè mí).

66. build (verb) kọ́: Olu built many housen round mine. (Olú kọ́ ọ̀pọ̀ ilé yí ilé mi ka).

67. bulge (verb); wú sóde: Olú bulge up some yame. (Olú wú iṣu sóde).

68. bulge (noun); Ìwúsóde: It’s bulge up beyond the usual size. (Ìwúsóde rẹ̀ ju bí ó se yẹ lọ).

69. bulk (noun): ìwọ̀n: Tankers Carry petroleum in bulk. (Ọkọ̀ elépo gbé epo ní ìwọ̀n).

70. bulky (adjective) Tóbi: She is bulky. (Ọmọ náà tóbi

71. bull (noun); akọ màálù: I take the bull by the horn. (Mo mu akọ màálù náà níbi ìwo).

72. bully (verb); kígbe mọ́: Olu bully on me. (Olú kígbe mọ́ mi).

73. bump (verb); kọlù: The blind man bumped unto me. (Ọkùnrin afójú náà kọlù mí).

74. bunch (noun); odidi: A bunch of banana was given to me. (Odidi ọ̀gẹ̀dẹ̀ ló fún mi).

75. bundle (noun) ẹrù: The bundle is heavy. (Ẹrù náà wúwo).

76. bundle (verb); di ẹrù: I bundled evenything into a box. (Mo di ẹrù papọ̀ sínú àpótí).

77. bungalow (noun); Irú ilé ilẹ̀ kan. Ayò’s house is a bungalow. (Ilé Ayọ̀ jẹ́ irú ile ilẹ̀ kan.

78. bunk (noun); ìbùsùn nínú ọkọ. The bunk was fixed on the wall. (Ìbùsùn inú ọkọ náà wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ògiri).

79. burden (noun) ìnira: He was always a burden to his parent. (Ọmọ náà jẹ́ ìnira fún àwọn òbí rẹ̀).

80. burgle (noun); olè: Set a burglar to catch a burglar. (Olè ni í mọ ẹsẹ̀ olè tọ̀ lorí àpáta).

81. burn (verb); sun: He burned some farm refuse. (Ó sun ilẹ̀ oko).

82. burrow (noun) ihò: I make a burrow for rabbit. (Mo gbẹ́ ihò fún ọ̀kẹ́rẹ́).

83. burst (verb); fọ́: We have to burst the door open. (A gbọ́dọ̀ fọ ilẹ̀kàn náà já).

84. bury (verb): sìnkú: He was buried at sea side. (Wọ́n sìnkí rẹ̀ sẹ́gbẹ̀ẹ́ odò)

85. bus (noun); ọ̀kọ̀ èrò: I entered a public bus. (Mo wọ ọkọ èrò).

86. bush (noun) igbó: There are many trees in the bush. (Ọ̀pọ̀lọpọ̀ igi ló wà nínú igbó) 87. business (noun); òwò: He has set up in business as a book seller. (Ọkùnrin náà ń se òwò ìwé títà).

88. butter (noun) lòrí àmọ́: I fried the eggs with butter. (Mo dín ẹyin pẹ̀lú òrí àmọ́).

89. button (noun); Òníní èwù: Button is in the dress she sew. (Òníní ẹ̀wù wà lára asọ tí ó rán).

90. Buy (verb) rà: Ayọ bought a car. (Ayọ̀ ra ọkọ ayọ́kẹ́lẹ́).

91. buzz (verb); Ìkin: The beez are buzzing along the road. (Àwọn oyin náà ń kùn káàkírì lẹ́gbẹ̀ẹ́ ojú ọ̀nà).

92. by (preposition); lẹ́bàá; My house is by the river. (Ilé mi wa lébàá odò).