Aubrey Plaza

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

 Aubrey Christina Plaza[1] (tí wọ́n bí ni June 26, 1984) [2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, aláwàdà, àti olùdárí. Ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn April Ludgate lórí NBC sitcom Parks àti Recreation láti 2009 – 2015, àti ìfihàn rẹ̀ nínú jara eré FX Legion (2017 – 2019). Ní ọdún 2022, ó kópa nínú eré àkọ́kọ́ tó jẹ́ apá keji anthology HBO The White Lotus, èyí sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe kan.

Aubrey Plaza
Plaza at WonderCon 2019
Ọjọ́ìbíAubrey Christina Plaza
26 Oṣù Kẹfà 1984 (1984-06-26) (ọmọ ọdún 40)
Wilmington, Delaware, U.S.
Ẹ̀kọ́
Iṣẹ́
  • Actress
  • comedian
  • writer
  • producer
Ìgbà iṣẹ́2006–present
Olólùfẹ́
Jeff Baena (m. 2021)

Lẹ́yìn tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré àti aláwàdà lórí ìtàgé Upright Citizens Brigade Theater, ó kópa gẹ́gẹ́ bí èdá-ìtàn kan nínú fíìmù Safety Not Guaranteed ní ọdún (2012). Ó tún ti farahàn nínú fíìmù Mystery Team ní ọdún (2009), Funny People ọdún (2009), Scott Pilgrim vs. World (2010), The To Do List (2013), Life After Beth ọdún (2014), Mike and Dave Need Wedding Dates (2016), Child's Play (2019), àti Happiest Season ọdún (2020). Plaza ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò, ó sì ti ṣàgbéjáde fíìmù bíi Awọn wakati Kekere (2017), Ingrid Goes West (2017).

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Plaza, Aubrey (March 1, 2012). "Aubrey Plaza Finally Confronts Her Multiple Personalities". Bullett Magazine. Archived from the original on January 19, 2013. Retrieved April 6, 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "UPI Alamanc for Saturday, June 26, 2021". June 26, 2021. https://www.upi.com/Top_News/2021/06/26/UPI-Almanac-for-Saturday-June-26-2021/9251624315114/.