Audrey Ajose
Audrey Olatokunbo Ajose (ọjọ́-ìbí c. 1937) jẹ́ Àgbẹjọ́rò àti Akòwé ọmọ Nàìjíríà. Ó ṣiṣẹ́ bí aṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ sí Scandinavia láti ọdún 1987 sí 1991. [1]
Omoba Audrey Olatokunbo Ajose | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1937 |
Iṣẹ́ |
|
Parent(s) |
|
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀ Àti Ẹ̀kọ́
àtúnṣeỌmọbìnrin Ọmọba Oladele Ajose àti Beatrice Spencer Roberts.[2] Audrey Ajose jẹ́ ọmọ obìnrin ilẹ̀ òkèèrè kan tí ó fẹ́ ọmọ Nàìjíríà. [3] Ó kọ ẹ̀kọ́ ìròyìn ní Regent Polytechnic. Ọ́ kọ ẹ̀kọ́ àti àdaṣe òfin ṣùgbọ́n tún tẹ̀síwájú láti ṣiṣẹ́ ní ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. [4] Ó tún kọ ẹ̀kọ́ nípa'theology' [5] [6]ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ nípa 'theology' ní ilé ìjọsìn Lutheran.
Àwọn Iṣẹ́ Tí A Yàn
àtúnṣe- Yomi's Adventures, juvenile fiction (1964)[7]
- Yomi in Paris, juvenile fiction (1966)
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Ajose, Audrey (Nigeria)". Literary Map of Africa. Ohio State University.
- ↑ "Tribute to Late Oladele Adebayo Ajose". The Sun (Nigeria). July 17, 2003. http://news.biafranigeriaworld.com/archive/2003/jul/17/0074.html.
- ↑ "Foreign women married Nigerians, nigerwives, foreign women in nigeria". nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-27.
- ↑ "Audrey Ajose | Academic Influence". academicinfluence.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-27.
- ↑ "AUDREY AJOSE: How I dared soldiers who held us captive in newsroom during 1985 coup - The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-11. Retrieved 2022-05-27.
- ↑ "MFR Audrey Olatokunbo Ajose". Government College Ibadan Old Boy's Association. Archived from the original on 2023-04-26. Retrieved 2023-04-26.
- ↑ "National Academic Digital Library of Ethiopia". ndl.ethernet.edu.et. Retrieved 2022-05-27.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]