Dona Aurelia Correia (d. circa 1875), ti a tumọ si Mae Aurelia, Mame Correia Aurelia ati Madame Oralia jẹ̀ óniṣowo oko ẹru ti Euro-Ilẹ Afrika[1][2].

Igbesi Àye Aurelia

àtúnṣe

Aurelia jẹ eniyan pataki ninu owo ṣiṣe ti Guinea-Bissau ni century ti ọkan dinlogun[3]. Arabinrin naa lo gbajumọ julọ ni agbègbè nhara ti wọn si wari fun ni ilẹ portuguese, a tun pe ni obinrin óniṣowo to ṣe pataki ni àṣa ilẹ Afrika[4]. Aurelia jẹ mọlẹbi Julia da Silva Cardoso[5] ati iyawo de facto ti óniṣowo Caetank Josè Nozolini (1800-1850), gomina ilẹ Portuguese ti Cape Verde. Aurelia jẹ óniṣowo oko ẹru lẹyin naa lo bẹrẹ sini gbin ẹ̀pa si inu oko ẹru nigba ti oko ẹru ilẹ̀ Afrika bẹ̀rẹ sini dinku ni ọdun 1830s. Arabinrin naa gbe awọn ẹpa naa lọsi awọn agbegbe Guinea eyi lo mu kodi agbẹ ẹpa to tobi julọ ni ilẹ Guinea nigbana.

Ilo awọn ẹru fun nkan agbẹ lo di ija lati ọdọ rẹ ati Squadron British iwọ oorun ilẹ Afrila ti wọn ja lu oko rẹ ni Bolama ni ọdun 1839 ati freetown ti wọn si gbe kuro ni Bolama ni ọdun 1860[6].

Ni ọdun 1850s, Aurelia ni ẹru ida mẹta to wa ni ilẹ̀ Guinea. Aurelia jẹ alagata larin ilẹ portuguese ati Guinea, larin portuguese ati British to si ko ipa pataki ninu óṣelu awọn agbegbe naa[7].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. Havik, Philip J (2015-12-29). "Aurélia Correia". Emmanuel K. Akyeampong & Henry Louis Gates (eds.) Dictionary of African Biography, Oxford: Oxford University Press, 2011: 124-126. https://www.academia.edu/19887330/Aur%C3%A9lia_Correia. Retrieved 2023-08-26. 
  2. Mark, P.A. (2002). "Portuguese" Style and Luso-African Identity: Precolonial Senegambia, Sixteenth - Nineteenth Centuries. "Portuguese" Style and Luso-African Identity. Indiana University Press. p. 161. ISBN 978-0-253-10955-2. https://books.google.com.ng/books?id=HdcR0J_huBAC&pg=PA161. Retrieved 2023-08-26. 
  3. "Correia, Mãe Aurélia". Oxford Reference. 2008-01-01. Retrieved 2023-08-26. 
  4. Brooks, G.E. (2010). Western Africa and Cabo Verde, 1790s-1830s: Symbiosis of Slave and Legitimate Trades. AuthorHouse. p. 213. ISBN 978-1-4520-8871-6. https://books.google.com.ng/books?id=AMa2VcbHbtEC&pg=PA213. Retrieved 2023-08-26. 
  5. Havik, P.J. (2004). Silences and Soundbites: The Gendered Dynamics of Trade and Brokerage in the Pre-colonial Guinea Bissau Region. Modernity and belonging. Lit. p. 310. ISBN 978-3-8258-7709-5. https://books.google.com.ng/books?id=ymkdf-PIYGoC&pg=PA310. Retrieved 2023-08-26. 
  6. Havik, P.J. (2004). Silences and Soundbites: The Gendered Dynamics of Trade and Brokerage in the Pre-colonial Guinea Bissau Region. Modernity and belonging. Lit. p. 204. ISBN 978-3-8258-7709-5. https://books.google.com.ng/books?id=ymkdf-PIYGoC&pg=PA204. Retrieved 2023-08-26. 
  7. Correspondence with the British Commissioners, at Sierra Leone, the Havana, Rio de Janeiro, and Surinam: From May 11th, to December 31st, 1840, inclusive. Correspondence with the British Commissioners, at Sierra Leone, the Havana, Rio de Janeiro, and Surinam: Relating to the Slave Trade, 1840 : Presented to Both Houses of Parliament by Command of His Majesty. William Clowes. 1841. p. 195. https://books.google.com.ng/books?id=HtZOAAAAYAAJ&pg=PA195. Retrieved 2023-08-26.