Aurelian
Adari Roomu
Aurelian jẹ́ Ọbalúayé ní Ilẹ̀ Ọbalúayé Róòmù. Àpèjá orúkọ rẹ̀ ni Lucius Domiticus Aurelianus. Ìwọ̀n ọjọ́ ayé rẹ̀ ni c 215-270, ìyàwó rẹ̀ ni Ulpia Severina, ọmọ re ni Waliballat, Vaballathus ni ede latin. O je ọbalúayé lẹ́yìn Quintillus. Ẹni àkọ́kọ́ tí ó ṣégun Alemanni àti Juthungi. Wọ́n kọ́ ògiri sí ilẹ̀ Róòmù ní orúkọ rẹ̀ ní 271. Wọ́n ṣe owó sílẹ̀ ní orúkọ rẹ̀ (coin of Aurellian).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |