Àdàkọ:Use mdy dates

Austin Abrams
Abrams in 2018
Ọjọ́ìbíAustin Noah Abrams
2 Oṣù Kẹ̀sán 1996 (1996-09-02) (ọmọ ọdún 28)
Iṣẹ́Òṣèré
Ìgbà iṣẹ́2011–present
Ọmọ ìlúSarasota, Florida, U.S.

Austin Noah Abrams tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejì oṣù Kẹsàán ọdún 1996[1] jẹ́ òṣèré ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré onípele àtìgbà-dégbà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtan Ron Anderson nínú ìpele ẹlẹ́kaàárùn ún eré The Walking Dead (2015–2016) Tí ó sì tún kópa nínú eré Euphoria gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn Ethan Lewis. Ó tún ti kópa nínú eré mìíràn bíi: The Kings of Summer (2013), Paper Towns (2015), Brad's Status (2017), àti Scary Stories to Tell in the Dark (2019).

Ìgbà èwe rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn òbí Abrams ni Lori ati Bradley Abrams tí wọ́n jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn. Wọ́n tọ́ Abrams dàgbà ní ìlú Sarasota, Florida.[2] Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Jew.[3]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Austin ni ó kópa gẹ́gẹ́ bí èdá ìtàn Ron Anderson nínú eré AMC The Walking Dead nínú ìpele Karùún àti ìpele kẹfà eré náà.[4] ní ọdún 2017, ó tún kópa bí ú eré tí ọ̀gbẹ́ni Kyle Wilamowski's kọ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ All Summers End, tí ó sì kópa gẹ́gẹ́ bí "Hunter Gorski"[5]

Ní ọdún 2017, Abrams tún kópa gẹ́gẹ́ bí "Troy" nínú eré apanilẹ́rìín Brad's Status.[6] Ó tún kó ipa tó pọ̀ nínú eré Scary Stories to Tell in the Dark ní ọdún 2019.[7] ní ọdún 2020, ó kópa gẹ́gẹ́ bí olú-èdá ìtàn nínú eré Chemical Hearts.[8]


Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Notes
2011 Ticking Clock James
2012 Jewtopia Young Adam Lipschitz
2013 Gangster Squad Pete
The Kings of Summer Aaron
2015 Paper Towns Ben Starling
Sacrifice Tim
2017 All Summers End Hunter Gorski
Brad's Status Troy Sloan
Tragedy Girls Craig Thompson
We Don't Belong Here Davey
2018 Dude James
Puzzle Gabe
2019 Scary Stories to Tell in the Dark Tommy Milner
2020 Chemical Hearts Henry Page

Eré orí amóhù-máwòrán

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Notes
2012 The Inbetweeners Todd Cooper 4 episodes
2014 Shameless Henry McNally Episode: "Emily"
Silicon Valley The Carver Episode: "Third Party Insourcing"
2015–2016 The Walking Dead Ron Anderson Recurring role; 9 episodes
2017 SMILF Casey Episodes: "1,800 Filet-O-Fishes & One Small Diet Coke" and "Mark’s Lunch & Two Cups Of Coffee"
2018 The Americans Jackson Barber Episodes: "Rififi"[9] and "The Summit"[10]
2019 Euphoria Ethan Lewis Recurring role; 6 episodes
2019–present This Is Us Marc Recurring role; 5 episodes
2020 Dash & Lily Dash Main role

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Palmieri, Lea (August 21, 2020). "Chemical Hearts Star Austin Abrams On The Art of Leaving An Awkward Voicemail". Decider. https://decider.com/2020/08/21/chemical-hearts-austin-abrams-interview/. Retrieved August 26, 2020. "[H]is 24th birthday is on September 2nd..." 
  2. "Sarasota's Austin Abrams Appears on AMC's The Walking Dead". Sarasota Magazine. Retrieved April 26, 2018. 
  3. "HBO's Euphoria, co-produced by Drake, is based on an Israeli show". April 16, 2019. 
  4. "'Walking Dead' Bosses Dissect "Big Pivotal Moment" in "Horrifying" Midseason Premiere". The Hollywood Reporter. Retrieved October 11, 2016. 
  5. "Austin Abrams and Beau Mirchoff Join Indie Drama Grass Stains". deadline.com. July 16, 2013. Retrieved July 17, 2013. 
  6. "Mike White on Brad's Status, Jack Black and The Emoji Movie". www.independent.co.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved September 8, 2020. 
  7. "Scary Stories to Tell in the Dark | SHOWTIME". SHO.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on August 9, 2020. Retrieved September 8, 2020. 
  8. Lattanzio, Ryan; Lattanzio, Ryan (July 29, 2020). "Chemical Hearts Trailer: Lili Reinhart, Austin Abrams Lead Amazon's Teen Heartbreaker". IndieWire (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved September 8, 2020. 
  9. Lea Palmieri (May 8, 2018). "Austin Abrams Is Hollywood's Go-To Cougar-bait". Decider. 
  10. Allison Shoemaker (May 16, 2018). "Between two conversations, The Americans do battle and seek absolution". The AV Club. Archived from the original on May 17, 2018. Retrieved November 30, 2020. 

Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:US-screen-actor-1990s-stub