Austin Okezie Meregini
Austin Okezie Meregini (tí a tún mọ̀ sí Ugolee) jẹ́ olóṣèlú àti aṣofin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń ṣojú gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlè Abia, tó ń ṣoju ẹkùn ìpínlẹ̀ Ìlà Oòrùn Umuahia. [1] O jẹ ọmọ ẹgbẹ òṣèlú ti Labour Party .
Austin Okezie Meregini | |
---|---|
Political party | Labour Party |