Awùjalẹ̀ Tí Ìjẹ̀bú

Awùjalẹ̀ jẹ́ orúkọ oyè Ọba ti ó nílẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ìjẹ̀bú-Òde ni ààfin Ọba Awùjalẹ̀ tèdó sí. Ọba Síkírù Káyọ̀dé Adétọ̀nà Ọ̀gbágbá II ni Awùjalẹ̀ Ìlú Ìjẹ̀bú tí ó wà lórí ìtẹ́ lọ́wọ́́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí Awùjalẹ̀ tí ilẹ̀ Ìjẹ̀bú pátápátá.[1] Ìdílé ọlọ́ba Aníkìláyà ló ti wá. [2]

Àwọn ìdílé Ọlọ́ba tí wọ́n máa ń jẹ́ Awùjalẹ̀ nílẹ̀ Ìjẹ̀bú.

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí òfin àti ìlànà ìbílẹ̀ tí là á kalẹ̀ lọ́dún 1959, àwọn ìdílé mẹ́rin péré ló ní àṣẹ láti jẹ òye ọba Awùjalẹ̀ tí ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Àwọn ìdílé ọlọ́ba náà ni;

  • 1. Ìdílé ọlọ́ba Gbélégbúwà
  • 2. Ìdílé ọlọ́ba Aníkìláyà
  • 3. Ìdílé ọlọ́ba Fúsẹ̀ngbuwà
  • 4. Ìdílé ọlọ́ba ìdípọ̀tẹ̀ [3]

Àtòjọ àwọn Awùjalẹ̀ tí wọ́n ti jẹ rí títí di òní

àtúnṣe
  • ỌBA OLÚ-ÌWÀ
  • ỌBA ỌṢÌN
  • OBAŃTA – 1430
  • ỌBA GÚRÚ – 1445
  • ỌBA MÚNIGBÚWÀ – 1455
  • OBAŃTA II – 1460
  • ỌBA LỌ́JAÀ – 1470
  • ỌBA LỌ́FIN – 1482
  • ỌBA APASA – 1496
  • ỌBA GANJU – 1508
  • ỌBA TEWOGBOYE – 1516
  • OBA RÚWÀMÚDÀ – 1520
  • ỌBA OFINRAN – 1532
  • ỌBA LÁPẸ́NGBÚÀ – 1537
  • ỌBA ÓTUTÙBÍỌSÙN – 1537
  • ỌBA MOKO IDOWA AJÚWÀKALẸ̀ – 1540
  • ỌBA ÀDÌSÁ – 1552
  • ỌBA JẸ́WỌ́ – 1561
  • ỌBA ẸLẸ́WÙ ÌLẸ̀KẸ̀ – 1576
  • ỌBA OLÚMISỌ́DÀN ẸLẸ́WÙ ÌLẸ̀KẸ̀ – 1590
  • ỌBA MASE – 1620
  • ỌBA OLÓTÙṢẸ̀ṢỌ́ – 1625
  • ỌBA MOLÀ – 1635
  • ỌBA ÀJÀNÀ – 1642
  • ỌBA ORE TÀBÍ GADÉGÚN – 1644 (The first female Awujale)
  • ỌBA GÚNWÀJÁ – 1655
  • ỌBA JADIARA TÀBÍ OLÓWÓJOYÈMÉJÌ – 1660
  • ỌBA ṢAPOKUN – 1675
  • ỌBA FÁLÓKUN – 1687
  • ỌBA MẸ́KÙN – 1692
  • ỌBA GBÓDOGI – 1702
  • ỌBA OJIGI AMÓYÈGẸ̀ṢỌ́ – 1710
  • ỌBA LIYEWE ARỌ̀JÒFÁYÉ – 1730
  • ỌBA MOYEGE ỌLỌ́PẸ́ – 1730
  • ỌBA Ọ̀JỌRÁ – 1735
  • ỌBA FẸ̀SỌ̀JOYÈ – 1745
  • ỌBA ORE JẸ́JEẸ́ – 1749 (ỌBABÌNRIN)
  • ỌBA SÁPẸ́NNÚWÀ RUBA KOYE – 1750
  • ỌBA ORÓDÚDU JOYÈ – 1755
  • ỌBA TẸWỌ́GBÙWÀ I – 1758
  • ỌBA GBÉLÉGBÚWÀ I – 1760
  • ỌBA FÙSẸ́NGBÚWÀ – 1790
  • ỌBA SẸ̀TẸ̀JOYÈ – 1820
  • ỌBA ANÍKÌLÁYÀ FIGBÀJOYÈ AGBÓÒGÙNSÁ – 1821
  • ỌBA AFÌDÍPỌ̀TẸ̀MỌ́LẸ̀ ADÉMÚYÈWÒ – 1850
  • ỌBA ATÚNWÀṢE ADÉSÌŃBỌ̀ – 1886
  • ỌBA Ọ̀GBÁGBÁ AGBỌ́TẸ̀WỌLẸ̀ I – 1895
  • ỌBA FÚSÌGBOYÈ ADÉỌ̀NÀ – 1906
  • ỌBA FẸSỌ̀GBADÉ ADÉMÓLÚ – 1916 (Dethroned)
  • ỌBA ADÉKỌ̀YÀ ELÉRÚJÀ – 1916
  • ỌBA ADÉMÓLÚ FẸSỌ̀GBADÉ – 1917 (Enthroned again)
  • ỌBA ADÉNÚGÀ AFỌLÁGBADÉ – 1925
  • ỌBA ÒGÚNNÁÌKÈ FIBIWOJÀ – 1929
  • ỌBA DANIEL ADEÉSÀNYÀ GBÉLÉGBÚWÀ II – 1933-1959
  • ỌBA Dr. SÍKÍRÙ OLÚWAKÁYỌ̀DÉ ADÉTỌ̀NÀ, Ọ̀GBÁGBÁ AGBỌ́TẸ̀WỌLẸ̀ II – 1960–present

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Omonhinmin, Gabriel (2017-01-15). "How I became The Awujale Of Ijebuland - The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2020-10-01. Retrieved 2019-12-01. 
  2. "THE EARLY HISTORY OF IJEBU on JSTOR". JSTOR. Retrieved 2019-12-01. 
  3. "Awujale - African ruler". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-12-01.