Awon
Antwan Wiggins tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹ́ta ọdún 1980 ( March 6, 1980) ní ìlú Brooklyn. jẹ́ ọ̀kọrin hip hop ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.[1] Orúkọ tí wọ́n mọ̀ọ́ pẹ̀lú rẹ̀ ni 'Awon'. Ní ọdún 2014, Ó dá ile- iṣẹ́ orin "Don't Sleep" kalẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Phoniks.[2][3] 'Awon' ti kọrin pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórin hip hop ilẹ̀ ̀Amẹ́ríkà bíi: Little Brother, Common, EPMD, MC Lyte, ati Oddisee.
Awon | |
---|---|
Awon in Newport News, Virginia | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Antwan Wiggins |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹta 1980 Brooklyn, New York |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Newport News, Virginia, U.S. |
Irú orin | Hip hop, alternative hip hop |
Years active | 2008–Present |
Labels | Don't Sleep Records |
Website | [1] |
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeSolo albums
àtúnṣe- Beautiful Loser (2008)
- For The Grimy (Searching For Soulville) (2013)
- Matte Black Soul (2014)
Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Phoniks
àtúnṣe- Return to the Golden Era (2013)
- Return to the Golden Era: The Remixes (2014)
- Knowledge of Self (2015)
Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Dephlow
àtúnṣe- Dephacation (2014)
- Sleep is the Cousin of Death (2017)
Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Kameleon Beats
àtúnṣe- Love Supersedes (2010)
- Concentration Gradient (2011)
- Love Supersedes II (2013)