Ayisat Yusuf
Ayisat Yusuf-Arómirẹ́ tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1985 (6 March 1985) agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ọmọ Nàìjíríà nígbà kan rí. Orílẹ̀-èdè Finland ni ó ń gbé báyìí.[1]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ayisat Yusuf-Arómirẹ́ | ||
Ọjọ́ ìbí | 6 Oṣù Kẹta 1985 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nàìjíríà | ||
Ìga | 1.62 m (5 ft 4 in) | ||
Playing position | ipò aàbò | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
–2007 | Nasarawa Amazons | ||
2007 | NiceFutis | – | (1) |
2007–2010 | Delta Queens FC | ||
2008 | KMF | - | (0) |
2010–2011 | Rivers Angels SC | ||
National team | |||
2002 | Ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà tí ọjọ́-orí wọn kò ju lọ | ||
2002–2009 | Ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Yusuf ti gbá bọ́ọ̀lù fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ní Nàìjíríà àti Finland. Ó wà lára Ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà lọ́dún fún ìdíje ife adúláwọ̀ lọ́dún 2004,ìdíje ife àgbáyé ti ọdún 2007,àti ìdíje Òlímpíkì ọdún 2008.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Falcons Good For AWC Trophy-Ayisat". SportsDay Online. Retrieved 2013-04-10.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]