Ayrton Senna da Silva (pèé [aˈiɾtõ ˈsenɐ da ˈsiwvɐ]  (Speaker Icon.svg listen); Ọjọ́ ọ̀kànlélógún Oṣùkẹta Ọdún 1960 - Ọjọ́ kínín Oṣù karún Ọdún 1994) jẹ́ eléré ìdárayá awakọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Brazil[1][2] tí ó gba Formula One lẹ́ẹ̀mẹta ní world championships. Ó kú nígbà tí ó ń ṣíwájú nínú ìdíje 1994 San Marino Grand Prix. Ikú rẹ̀ ni ó kẹ́yìn nínụ ìdíje fún Formula One.[3]

Ayrton Senna
Ayrton Senna 8 - Cropped.jpg
Born (1960-03-21)21 Oṣù Kẹta 1960
São Paulo, Brazil
Died 1 May 1994(1994-05-01) (ọmọ ọdún 34)
Bologna, Italy
Formula One World Championship career
Nationality  Brazilian
Active years 19841994
Teams Toleman, Lotus, McLaren, Williams
Races 162 (161 starts)
Championships 3 (1988, 1990, 1991)
Wins 41
Podiums 80
Career points 610 (614)
Pole positions 65
Fastest laps 19
First race 1984 Brazilian Grand Prix
First win 1985 Portuguese Grand Prix
Last win 1993 Australian Grand Prix
Last race 1994 San Marino Grand Prix

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe