Abdelaziz El Idrissi Bouderbala ni a bini ọjọ kẹrin din lọgbọn, óṣu December ni ọdun 1960 jẹ elere bọọlu afẹsẹgba nigba kan ri. Ni ọdun 2006, elere naa jẹ okan lara awọn igba elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ni ilẹ afirica ti CAF yan fun adọta ọdun sẹyin[1][2][3].

Aziz Bouderbala
Aziz_Bouderbala,_Lalla_plus_-_Feb_12,_2018
Personal information
OrúkọAbdelaziz El Idrissi Bouderbala
Ọjọ́ ìbí26 Oṣù Kejìlá 1960 (1960-12-26) (ọmọ ọdún 64)
Ibi ọjọ́ibíMorocco
Ìga1.78 m (5 ft 10 in)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1977–1984Wydad Casablanca(–)
1984–1988FC Sion88(25)
1988–1990Racing Levallois 9249(15)
1990–1992Olympique Lyonnais54(10)
1992–1993G.D. Estoril Praia24(4)
1993–1995FC St. Gallen34(3)
Total249(57)
National team
1979–1992Morocco national football team57(14)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Iṣẹ elere naa ati Àṣèyọri

àtúnṣe

Aziz bẹrẹ iṣẹ rẹ gẹgẹbi àkọṣẹ mọṣẹ elere bọọlu afẹsẹgba ni Wydad Casablanca kotodipè o lọ si FC Sion,Matra Racing ati French Olympique Lyon[4]. Ni ọdun 1986, Bouderbala gba ami ẹyẹ gẹgẹbi elere bọọlu afẹsẹgba ti ọdun naa. Ni ọdun 1986, Arakunrin naa ṣèrè ni Cup Finals agabaye ti FIFA[5][6]. Ni ọdun 1988, Aziz jẹ elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ninu Cup Nations ti ilẹ Afirica[7]. Ni ọdun 2015, Aziz jẹ Aṣoju fun SATUC Cup, eleyi lo jẹ idije tutun lori bọọlu afẹsẹgba fun awọn ọmọ órukan U16, ọmọ alaina ati atọrọjẹ[8][9][10].

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Africa Player of the Century
  2. Best player of the last 50 years 14 Moroccans in the running
  3. Aziz profile
  4. Abdelaziz Bouderbala
  5. World Cup
  6. Aziz Bouderbala
  7. Africa Cup of Nations
  8. SATUC Cup Ambassador
  9. Aziz Bouderbala, former Moroccan national and international footballing star as team Ambassador,
  10. "SATUC CUP AMBASSADOR 2017". Archived from the original on 2023-03-15. Retrieved 2023-03-15.