Bàlúṣì tàbí Bàlóṣì

Baluchi or Balochi

Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó múlíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye.[1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Baluchi language, alphabet and pronunciation". Omniglot. 2019-06-16. Retrieved 2019-11-20. 
  2. "The Balochi Language Project - Uppsala universitet". Institutionen för lingvistik och filologi. 2019-11-15. Archived from the original on 2019-08-25. Retrieved 2019-11-20.