Bàtà
Bàtà jẹ́ ohun tí ọmọ ènìyàn ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti lè fi rìn ati láti se dáàbòbò ẹsẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjàmbá tó lè ṣakóbá fún ẹsẹ̀ [1]
Ìwúlò bàtà
àtúnṣeWọ́n ma ń lo bàtà yálà lásìkò ẹ̀rùn tàbí òjò. Wọ́n ń lo bàtà láti fi ṣe iṣẹ́ èyíkéyí, ṣe eré ìdárayá, ṣe ìdáàbòbò ara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [2] Láì Ko sí bàtà láyé Òde òní, ó lè ṣòro fún ọmọnìyàn láti ṣe ohunkóhun dára dára bí wọn ko bá wọ bàtà sí ẹsẹ̀.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Home". Bata Nigeria. Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "BRAND REVIEW: THE RETURN OF BATA". Mapemond Resources. 2019-04-09. Archived from the original on 2020-08-06. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ DianaAbasi, Iquo. "Bàtà Ìwọ̀seré Aláwọ̀ Èsúrú". OlongoAfrica Multilingual Anthology. Retrieved 2024-08-18.