Bólshéfìk
Àwọn Bólshéfìk, ni bere bi[1] Bolshevists[2] (Rọ́síà: большевики, большевик (singular) Pípè ní èdè Rọ́síà: [bəlʲʂɨˈvʲik], to wa lati bol'shinstvo, "ogunlogo", to hun na wa lati bol'she, "ju", iru oro ijuwe bol'shoi, "titobi") ni won je eka Marxisti Egbe Olosise Tolosearailu Awujo Rosia (RSDLP) to pin soto lodo eka Menshefik[3] ni ibi Kongres Keji Egbe ni 1903.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Ushakov's Explanatory Dictionary of Russian Language, article "Большевистский"
- ↑ Dictionaries define the word "Bolshevist" both as a synonym to "Bolshevik" and as an adherent of Bolshevik policies.
- ↑ Derived from men'shinstvo, "minority", which comes from men'she, "less". The split occurred at the Second Party Congress in 1903.