Bọ̀dé Ṣówandé ni a bí ní ọjọ́Kejì oṣù Karùún, ọdún 1948 (2-05-1948), jẹ́ Ònkọ̀wé, Eléré oníṣe àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ònkọ̀wé

àtúnṣe

Ó jẹ́ olùkọ iwe nípa ọmọnìyàn àti ìṣesí àwùjọ. Ó jẹ́ ònkọ̀wé tí ó ma ń lo àwọn ọgbọ́n àtinúdá tí a ṣe lọ́jọ̀ pẹ̀lú àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá.[2] Ṣówandé wà lára ọ̀wọ́ ìpele ìran àwọn ònkọ̀wé Kejì nílẹ̀ Nàìjíríà, tí wọ́n ma ń kẹ́fin sí ètò ìṣèlú, bí a ṣe lè dara pọ̀ àti lòó fún ìgbéga ìṣẹ̀mí ìlú àti ènìyàn gbogbo nínú àpilẹ̀kọ wọn gbogbo.[3] Lára àwọn ikọ̀ rẹ̀ ni: Zulu Ṣófọlá, Fẹ́mi Osofisan àti Festus Iyayi.[4]Bọ̀dé Ṣówandé fi ìtàkùn website rẹ̀ tíó pè ní Tarot lọ́ọ́lẹ̀ ní Ọjàọ́ Karùún ọdún 2010. Tarot With Prayers òun lò sì tún ni [1] Òun lò ni "Odu Themes", àti "Bọ̀dé Ṣówandé Theatre Academy", tí ó jẹ́ àyè ìkọ́ni fún àwọn òṣèré.[5]

Ẹbí rẹ̀

àtúnṣe

Ó fẹ́yàwó, ó sì bímọ.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Revolvy, LLC (1948-05-02). ""Bode Sowande" on Revolvy.com". Revolvy. Retrieved 2019-12-29. 
  2. Admin (2017-11-23). "Prof Sowande, Omobude To Be Hosted By ANA Oyo On Saturday". PM Parrot. Retrieved 2019-12-29. 
  3. Osita Okagbue, African Writers Vol. 2 1997
  4. Abolo, Greg (2018-05-10). "Performing Artists Gather At Ibadan Varsity For Bode Sowande At 70 – The Oasis Reporters". The Oasis Reporters – News on time, everytime. Retrieved 2019-12-29. 
  5. "Bode Sowande Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2019-12-29. Retrieved 2019-12-29.