Bọlaji Ẹniọla Maryam
Ẹ̀niọla Maryam jẹ àkọṣemọṣẹ elere badminton orilẹ ede Naigiria ti à bini 21, óṣu september ni ọdun 2005 ni ilu ibadan ṣugbọn ó dàgbà si ipinlẹ kwara Naigiria. Arabinrin na fi oju si ere tennis tẹlẹ tẹlẹ ki oto wa dipe o pada si ère badminton[1].
Aṣeyọrì
àtúnṣeBọlaji jẹ ẹni akọkọ ni ilẹ Afirica lati gba gold ni championship lori badminton ti o si pegede lati lọ kopa ni ere idije badminton ni ilu japan[2][3].