B S Hùndéyín
B S Hùndéyín tí wọ́n bí ní oṣù kẹta ọdún 1934 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú àti olùkọ́ ọmọ bíbí Ògù láti ìlú Badagry ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Nígbà ayé rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́, olùkọ́-àgbà, kọmiṣọ́nnà ní ìpínlẹ̀ Èkó àti àgbà òṣèlú. [1]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "HUNDEYIN, Chief B. S.". Biographical Legacy and Research Foundation. 2017-03-02. Retrieved 2019-12-29.