Babatunde Osotimehin
Babatunde Osotimehin (ojo kefa osu keji ni odun 1949 – ojo kerin osu kefa ni odun 2017) O je onisegun oyinbo ni orile ede naijiria, Osimhen sise gege bi Minisita eka eto ilera, and ni odun 2011osi je oludari agba fun United Nations Population Fund, osi tun di ipo Under-Secretary-General of the United Nations, Atunyan si ipo sii waye ni osu kejo ni odun 2014 titi to fi papoda. Osotimehin si je eni toni afoju sun lori oro odo ati isako sabo, ati o ṣiduro fun ilera ibisi ati awọn ẹtọ ibisi, ni pataki laarin ipo ti ajakale-arun HIV. Ọkan ninu awọn agbara rẹ ni igbẹkẹle rẹ lori data ati ẹri.[2]
Prof. Babatunde Osotimehin | |
---|---|
Osotimehin speaking at the London Summit on Family Planning in 2012 | |
Executive Director of UNFPA, the United Nations Population Fund | |
In office 1 January 2011 – 4 June 2017 | |
Asíwájú | Thoraya Obaid |
Arọ́pò | Natalia Kanem |
Minister of Health | |
In office 17 December 2008 – 17 March 2010 | |
Asíwájú | Adenike Grange |
Arọ́pò | Onyebuchi Chukwu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 February 1949 Ogun State, Nigeria |
Aláìsí | 4 June 2017 New York City, United States[1] | (ọmọ ọdún 68)
Àwọn ọmọ | 5 |