Babute jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ Áfríkà, ó jẹ́ oúnjẹ tí a fi ẹran ṣe, tí ó ṣẹ̀ láti ẹ̀yà Babute ní orílẹ̀-èdè Congo. Àwọn èròjà oúnjẹ yìí ni ẹran lílọ̀, curry, àti ápíkrọ́tì.
Àdàkọ:African cuisine
Àdàkọ:Africa-cuisine-stub